domingo, 28 de dezembro de 2014

Os numerais yorubás



Àwọn iye yorùbá.
Os numerais yorubás




1-Ení / ọ̀kan
2-Èjì
3-Ẹta
4-Ẹrin, 
5-Àrún
6-Ẹfà
7-Èje
8-Ẹjọ
9-Ẹsan
10-Ẹwa
11-Ọkanla
12-Ejila
13-Ẹtala
14-Ẹrinla
15-Ẹdogun
16-Ẹrindinlogun
17-Ẹtadinlogun
18-Ejindinlogun
19-Ọkandinlogun
20-Ogun
21-Ọkanlelogun
22-Ejilelogun
23-Ẹtalelogun
24-Ẹrinlelogun
25-Ẹdọgbọn
26-Ẹrindinlọgbọn
27-Ẹtadinlọgbọn
28-Ejidinlọgbọn
29-Ọkandinlọgbọn
30-Ọgbọn
31-Ọkanlelọgbọn
32-Ejilelọgbọn
33-Ẹtalelọgbọn
34-Ẹrinlelọgbọn
35-Arundinlogoji
36-Ẹrindinlogoji
37-Ẹtadinlogoji
38-Ejidinlogoji
39-Ọkandinlogoji
40-Ogoji
41-Ọkanlelogoji
42-Ejilelogoji
43-Ẹtalelogoji
44-Ẹrinlelogoji
45-Arundinladọta
46-Ẹrindinladọta
47-Ẹtadinladọta
48-Ejidinladọta
49-Ọkandinladọta
50-Adọta
51-Ọkanleladọta
52-Ejileladọta
53-Ẹtaleladọta
54-Ẹrinleladọta
55-Arundinlọgọta
56-Ẹrindinlọgọta
57-Ẹtadinlọgọta
58-Ejidinlọgọta
59-Ọkandinlọgọta
60-Ọgọta
61-Ọkanlelọgọta
62-Ejilelọgọta
63-Ẹtalelọgọta
64-Ẹrinlelọgọta
65-Arundiladọrin
70-Adọrin 
71-Ọkanleladọrin
72-Ejileladọrin
73-Ẹtaleladọrin
74-Ẹrinleladọrin
75-Arundilọgọrin
76-Ẹrindilọgọrin
77-Ẹtadilọgọrin
78-Ejidilọgọrin
79-Ọkandilọgọrin
80-Ọgọrin
81-Ọkanlelọgọrin
82-Ejilelọgọrin
83-Ẹtalelọgọrin
84-Ẹrinlelọgọrin
85-Arundiladọrun
86-Ẹrindiladọrun
87-Ẹtadiladọrun
88-Ejidiladọrun
89-Ọkandiladọrun
90-Adọrun 
91-Ọkanleladọrun
92-Ejileladọrun
93-Ẹtaleladọrun
94-Ẹrinleladọrun
95-Arundilọgọrun
96-Ẹrindilọgọrun
97-Ẹtadilọgọrun
98-Ejidilọgọrun
99-Ọkandilọgọrun
100-Ọgọrun