terça-feira, 18 de julho de 2023

- Questões fundamentais

 Àwọn ìbéèrè pàtàkì (questões fundamentais) 

Kéèyàn tó lè ní ojúlówó ìbàlẹ̀ ọkàn, èèyàn ní láti rí ìdáhùn sáwọn ìbéèrè pàtàkì yìí - Se você quiser ter verdadeira paz mental, precisa obter respostas para estas perguntas fundamentais: 

1. Ta ni àwọn èèyàn mi, ta sì ni èmi? - Quem é o meu povo e quem sou eu?

2. Ibo làwọn èèyàn mi ti wá? - De onde veio o meu povo? Níbo ni mo ti wá?  - De onde eu vim? Báwo ni mo ṣe dáyé? - De onde eu vim?

3.  Ibo ni àwọn ènìyàn mi ń lọ? - Para onde meu povo está indo? Níbo ni mo ń lọ? - Para onde estou indo?

4. Kí làwọn èèyàn mi ń ṣe nínú ayé yìí? - O que meu povo está fazendo neste mundo? Kí ni mò ń ṣe nínú ayé yìí? O que estou fazendo neste mundo?