sexta-feira, 17 de dezembro de 2021

Seleção Haitiana de Futebol

Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ ọmọorílẹ̀-èdè Hàítì.

Seleção Haitiana de Futebol.


Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações:
https://www.hojeemdia.com.br/esportes/sele%C3%A7%C3%A3o-do-haiti-joga-pela-alegria-e-esperan%C3%A7a-de-seu-povo-1.390021

Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò, àkójọ ọ̀rọ̀ tí ò ń lò lójoojúmọ́, àwọn àkànlò ọ̀rọ̀, àwọn àkànlò èdè, ọ̀rọ̀ tó máa ń sọ, àkànlò èdè lọ́nà tó gún régé (vocabulário).


Nwọ́n, pron. pess. Eles, elas. Expressa uma ação que não é creditada a nenhuma pessoa em particular.

Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas. É também usado como partícula para formar o plural do substantivo; neste caso, é posicionado antes do substantivo.

Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.

Wọn, pron. poss. Deles, delas.

Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀, s. Seleção de futebol.
Ẹgbẹ́, s.  Sociedade, associação, clube, partido. Companheiro, par. Posição, classe.

Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀, s. Time de futebol.
Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù ńlá kan, s. Um grande time de futebol.

Eré bọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá, bọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá, s. Futebol.

Gbá bọ́ọ̀lù, v. Jogar futebol.

Agbábọ́ọ̀lù, s. Jogador de futebol.
Àwọn agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀, s. Futebolistas, jogadores de futebol.

Bọ́ọ̀lù, s. Bola (do inglês ball).
Ẹlẹ́sẹ̀, s. Lacaio, acompanhante, que visita os amigos.

Orílẹ̀-èdè Hàítì, ilẹ̀ Hàítì, s. Haiti.

Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Hàítì, s. República do Haiti.

Ọmọ orílẹ̀-èdè Hàítì, ọmọ ilẹ̀ Hàítì, s. Haitiano, haitiana.

Ti orílẹ̀ èdè Hàítì, adj. Do Haiti. 

Tó jẹ́ ọmọ bíbí ilẹ̀ Hàítì, tí a bí ní ilẹ̀ Hàítì, adj. Haitiano, haitiana.

Obìnrin ọmọ Hàítì, obìnrin ọmọ ilẹ̀ Hàítì, obìnrin ará Hàítì, obìnrin tó jẹ́ ọmọ bíbí ilẹ̀ Hàítì, s. Mulher haitiana.  

Ọkùnrin ọmọ Hàítì, ọkùnrin ilẹ̀ Hàítì, 

ọkùnrin ará Hàítì, ọkùnrin tó jẹ́ ọmọ bíbí ilẹ̀ Hàítìs. Homem haitiano.

Ilẹ̀, s. Terra, solo, chão. 

Orílẹ̀-èdè Olómìnira, s. República.
Ìpínlẹ̀, orílẹ̀-èdè, s. Estado.
Ìpínlẹ̀, s. Fronteira, demarcação, limite entre duas cidades, Estado ( SP, RJ).
Orílẹ̀, s. Nome que denota um grupo de origem ou clã.
Orílẹ̀-èdè, s. Estado, nação.

Ìlú, s. Cidade, terra, , região, país.
Ìlù, s. Tambor, um tipo de toque de atabaque.
Ìlù, s. Atabaque, tambor.
Ìlu, s. Verruma, perfurante.
Ìlú etí, s. Tímpano.
Èdè, s. Idioma, língua, dialeto.
Olómìnira, adj. Independente.