Ìdínkù àkókò ti ènìà di ọkùnrin tàbí obìnrin ìwàọ̀daràn.
Redução da maioridade penal.
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário).
Ìdínkùìbùkù, ìdínkù, ìbùkù, s. Redução.
Àkókò ti ènìà di ọkùnrin tàbí obìnrin, s. Maioridade.
Arúfin, ẹlẹ́ṣẹ̀ ọ̀dáràn, s. Criminoso, criminosa, facínora.
Ọ̀daràn, s. Criminoso, malfeitor, culpado.
Ìgbẹ́kẹ̀lé, ẹrù, s. Responsabilidade, confiança.
Ẹrù, s. Carga, bagagem.
Ìgbẹ́kẹ̀lé-ara-ẹni, s. Autoconfiança.
Ìjìyà, s. Sofrimento, pena.
Ìyà, ìjìyà, ìjẹníyà, s. Punição, castigo, pena.
Ìṣẹ́níṣẹ́, ìṣẹ́níṣẹ̀ẹ́, s. Maus-tratos, pena, empobrecimento, esgotamento.
Ìjáyà, s. Medo, pavor, terror, fobia.
Ilé-Ẹjọ́ Ìwàọ̀daràn Káríayé, s. Corte Penal Internacional.