Ère arabarìbì kan tó ń bọlá fún ẹni tó ti pa àwọn ẹ̀yà ìran run.
Uma enorme estátua que honra um genocida.
Estátua de Borba Gato em chamas em Santo Amaro, SP – Foto de Sato do Brasil
Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações:
https://jornalistaslivres.org/borba-gato-a-estatua-de-um-genocida-estuprador-e-escravagista-que-merece-arder-em-chamas/
Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò, àkójọ ọ̀rọ̀ tí ò ń lò lójoojúmọ́, àwọn àkànlò ọ̀rọ̀, àwọn àkànlò èdè, ọ̀rọ̀ tó máa ń sọ, àkànlò èdè lọ́nà tó gún régé (vocabulário).
Nwọ́n, pron. pess. Eles, elas. Expressa uma ação que não é creditada a nenhuma pessoa em particular.
Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas. É também usado como partícula para formar o plural do substantivo; neste caso, é posicionado antes do substantivo.
Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.
Wọn, pron. poss. Deles, delas.
Ère arabarìbì kan, s. Uma estátua enorme.
Tó máa ń bọlá fún, adj. Que honra.
Tó máa ń buyì àti ọlá fáwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ tó wà lórí ilẹ̀ ayé, adj. Que dignifica e honra seus servos terrestres.
Bọlá fún, v. Honrar, respeitar ou manter uma grande estima.
Ẹni tó ti pa àwọn ẹ̀yà ìran run, s. Aquele que destruiu etnias.
Ẹni tó máa ń pa àwọn ẹ̀yà ìran run, ẹni tó máa ń pa àwọn ẹ̀yà run, s. Aquele que extermina etnias, genocida.