Fídíò lórí arábìnrin mẹ́ta ilẹ̀ Túrkì.
Vídeo sobre três irmãs da Turquia.
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário).
Fídíò, s. Vídeo
Lórí, lérí, prep. Sobre, em cima de.
Arábìnrin, s. Irmã.
Mẹ́ta, num. Total de três.
Ilẹ̀, s. Terra, solo, chão.
Túrkì, s. Turquia.