Àwọn àkọsílẹ̀ ara ẹni, àwọn àkọsílẹ̀ gbogbo gbòò, tàbí lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì.
Documentos pessoais, documentos públicos ou na Internet.
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário).
Ìwé àṣẹ, àkọsílẹ̀, ìwé, s. Documento. Ìwé aṣẹ iṣẹ-aje igbaani ti a fi papirọọsi ṣe lati gbe ero ohun kan ti o mu ìní ọjọ iwaju daniloju yọ - Documentos comerciais de papiro para transmitir a idéia de algo que garante a posse futura.
Ìwé àṣẹ ìdánimọ̀, ìwé ìdánimọ̀, nọ́ńbà ìdánimọ̀, káàdì ìdánimọ̀ tí ìjọba àpapọ̀, s. Documento de Identidade.
Ìwé ẹ̀rí ọjọ́ ìbí, s. Certidão de nascimento.
Ìwé ẹ̀rí ìgbéyàwó, s. Certidão de casamento.
Ìwé ẹ̀rí ìrẹ́pọ̀ lọ́kọláya tí ó fẹsẹ̀múlẹ̀, s. Certidão de União Estável.
Ìwé àṣẹ ìwakọ̀, s. Carteira de motorista.
Ìwé àṣẹ iṣẹ́, s. Carteira de trabalho.
Ìwé kọpamọ́, s. Livro de Registro.
Ìwé ẹ̀rí, s. Certidão, certificação, diploma, recibo.
Ìwé ẹ̀rí dípúlọ́mà, s. Diploma.
Ìwé-ìhágún, s. Testamento.
Ìwé-ìròkèèrè, ìwé àṣẹ ìrìn àjò, s. Passaporte.
Ìwé-ìwọlé, ìwé ìrajà àwìn, káàdì ìrajà àwìn, s. Cartão de crédito.
Ìwé-owó, s. Talão de cheque.
Ìwé ilé, s. Escritura da propriedade.
Ìwé ìdìbò, s. Cédula. Papel com nome de candidato a cargo eletivo; chapa eleitoral; voto.
Káàdì ìdánimọ̀ onígbà kúkúrú tó ń fi hàn pé mo ṣẹ̀ṣẹ̀ ti ogun dé ni, s. Carteira de identidade temporária para minha repatriação.
Àwọn ìwé àdéhùn ọjà, s. Documentos comerciais.
Ìwé ẹ̀rí ìlera tó yẹ, s. Atestado de saúde apropriado.
Ìwé ẹ̀rí ìṣègùn, s. Atestado médico.
Ìwé ẹ̀rí pé ẹnì kejì rẹ ti kú, s. Certidão de óbito, certificado que seu cônjuge morreu.
Ìwé ẹ̀rí ìyìn, s. Diploma de mérito.
Oyè tí wọ́n gbà sẹ́yìn orúkọ wọn, s. Títulos acadêmicos.
Àkọsílẹ̀ owó tó wà ní báńkì, s. Extrato bancário.
Rìsíìtì ọjà tó o rà, s. Comprovante de compra e venda.
Rìsíìtì, s. Recibo, comprovante.
Ìforúkọsílẹ̀ kan ṣoṣo, s. Cadastro único.
Ẹ̀ri àdírẹ́sì, s. Comprovante de endereço. Owó tá à ń san fún iná mànàmáná - Conta de luz.
Owó tá à ń san fún omi - Conta de água.
Owó tẹlifóònù, s. Conta de telefone.
Ìwé àdéhùn, s. Contrato.
Ìwé orúkọ àwọn olùdìbò, s. Registro de eleitores, cadastros eleitorais.
Rìsíìtì ọjà tó o rà, kí orúkọ ẹni tó ta ọjà náà àti àdírẹ́sì onítọ̀hún sì wà lára rìsíìtì náà, s. Comprovante de compra e venda com o nome e o endereço do vendedor.
Káàdì Ìdánimọ̀ fún àwọn ọmọ wọn, s. Cartão de Identidade para seus filhos.
Káàdì olùdìbò, s. Cartão do eleitor, título de eleitor, título eleitoral.
Ìwé àfàṣẹsí, ìwé àṣẹ, s. Documento oficial.
Ìwé ìròyìn ìjọba, s. Diário oficial.
Ìforúkọsílẹ̀ ẹni tara, s. Cadastro de Pessoa Física (CPF).
Ìwé aṣẹ oko, s. Escritura da propriedade rural.
Ìwé aṣẹ oko kéékèèké, ìwé aṣẹ oko kékeré, s. Documento do sítio.