Kàlẹ́ńdà àwọn ará Kẹ́mẹ́ẹ̀tì
Calendário do povo de Kemet.
Feliz feliz ano novo 6259 para todos os africanos autênticos (Kamitas).
Kàlẹ́ńdà tí a kà sí elédè mẹ́ta (calendário trilíngue): èdè yorùbá (língua Yorùbá), èdè Íjíbítì (língua Egípcia, r n km.t), èdè Potogí (língua Portuguesa).
Àwọn oṣù tí ḿbẹ nínú ọdún (meses do ano):
1. Oṣù kínní ọdún, ṣẹ́rẹ́ (djehouty, janeiro).
2. Oṣù kejì ọdún, erélú (pan ipet, fevereiro).
3. Oṣù kẹta ọdún, erénà (hout-horo, março).
4. Oṣù kẹrin ọdún, igbe (ka-her-ka, abril).
5. Oṣù karùn-ún ọdún, èbìbí (ta-aabet, maio).
6. Oṣù kẹfà ọdún, okódù (fa-n-mekherou, junho).
7. Oṣù keje ọdún, agẹmọ (pa-n-imanhotepou, julho).
8. Oṣù kẹjọ ọdún, ògún (pa-n-nennout, agosto).
9. Oṣù kẹsàn-án, owéwè (pa-n-khonsou, setembro).
10. Oṣù kẹwà-á ọdún, ọ̀wàwà (pa-n-inet, outubro).
11. Oṣù kọkànlá ọdún, belu (ep-ipi, novembro).
12. Oṣù kejìlá ọdún, ọ̀pẹ (mesout-ra, dezembro).
Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações:
https://web.facebook.com/530029234035375/posts/feliz-ano-novo-para-todos-os-kamites-africanos-faz-6257-anos-desde-que-nossos-an/1145265745845051/?_rdc=1&_rdr
https://afrikhepri.org/pt/retour-au-calendier-africain/
https://comozed.com/em-que-ano-est%C3%A1-no-calend%C3%A1rio-eg%C3%ADpcio
Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò (vocabulário), àwọn ọ̀rọ̀ tá a sábà máa ń sọ ( palavras comuns), àwọn ọ̀rọ̀ tá a sábà máa ń lò (palavras que usamos frequentemente), àkójọ ọ̀rọ̀ tá à ń lò lójoojúmọ́ (vocabulário do dia a dia), àlàyé ọ̀rọ̀, àlàyé àwọn ọ̀rọ̀ (glossário), àkójọ ọ̀rọ̀ (glossário, lista de palavras), àkójọ ọ̀rọ̀ púpọ̀ lágbárí (uma grande lista de palavras na cabeça), àkópọ̀ wóróhùn ọ̀rọ̀ dídára tí o mọ̀ (uma coleção de boas palavras que você conhece).
Nwọ́n, pron. pess. Eles, elas. Expressa uma ação que não é creditada a nenhuma pessoa em particular.
Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas. É também usado como partícula para formar o plural do substantivo; neste caso, é posicionado antes do substantivo.
Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.
Wọn, pron. poss. Deles, delas.
Ẹ̀kọ́ Nípa nípa ìtàn Íjíbítì, ìmọ̀ nípa ìtàn Íjíbítì, s. Egiptologia.
Onímọ̀ nípa àwọn ohun ìṣẹ̀ǹbáyé ilẹ̀ Íjíbítì, ẹlẹ́kọ̀ọ́ nípa ohun ìṣẹ̀ǹbáyé Íjíbítì, ẹlẹ́kọ̀ọ́ nípa ilẹ̀ Íjíbítì, s. Egiptólogo.
Ọ̀jọ̀gbọ́n nípa ìtàn Íjíbítì, s. Professor de egiptologia.
Ìtàn Íjíbítì, s. História do Egito.
Ilẹ̀ Kẹ́mẹ́ẹ̀tì, Kẹ́mẹ́ẹ̀tì, s. Kemet, Egito antigo. A palavra Kemet foi escrita em Medu Neter, linguagem escrita mais antiga da Terra, com quatro hieróglifos.
Ẹ́gíptì, Íjíbítì, s. Egito.
Orílẹ̀-èdè Olómìnira Árábù ilẹ̀ Ẹ́gíptì, s. República Árabe do Egito.
Ẹ́gíptì Ayéijọ́un, s. Egito antigo.
Ọlọ́run oòrùn tí wọ́n ń pè ní Ráà, s. Deus-sol Rá.
Àwọn òrìṣà ilẹ̀ Íjíbítì, s. Deuses do Egito.
Hórúsì, s. Hórus.
Ósírísì, s. Osíris.
Ísísì, s. Ísis.
Ìtàn, s. Mitos, histórias.
Àtijọ́, s. Tempo antigo.