terça-feira, 19 de março de 2019

Lobisomens

Àwọn ṣẹranko-ṣènìyàn (lobisomens).

Resultado de imagem para lobisomem



Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Para mais informações:

https://brasilescola.uol.com.br/folclore/lobisomem.htm


Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).



Léfíátánì, s. Leviatã: monstro marinho, dragão marinho. O mais terrível dos monstros marinhos. 
Ẹran ńlá abàmì inú òkun, s. Monstro marinho.
Ewèlè, s. Um espírito das florestas, monstro. Pessoa com grande habilidade.
Ohun ibanilẹ̀ru, ewèlè, ìlòdìsí ìwà ẹ̀dá, nkan títóbijù. s. Monstro.
Fanpaya, àǹjọ̀nnú, s. Vampiro.
Sátánì, s. Diabo, capeta, satã.

Bìlísì, s. Mal, demônio, diabo.
Lúsíférì, s. Lúcifer.

Èèyàn tó lẹ́mìí òkùnkùn, s. Pessoa possuída por um demônio.
Òkú, s. Morto, cadáver. Àwọn fíìmù tó ń dẹ́rù bani  ló ń mú kí àwọn èèyàn gbà gbọ́ pé àkúdàáyà (òkú tó ń fara hàn káàkiri) wà - É, os filmes de terror fazem com que muitos acreditem em fantasmas.
Ìrora Láìsọ́gbẹ́, s. Dor fantasma.
Fíìmù tó ń dẹ́rù bani, s. Filme de terror.