Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.
Mo gba ìmọ̀ràn náà. Eu aceitei a sugestão. Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário). Ìmọ̀ràn, ìmọ̀, s. Conselho, opinião, conhecimento. Ìmọ̀rọ̀, s. Conselho, aviso. Mo, pron. pess. Eu. Gbà, v. Receber, tomar, pegar. Aceitar, admitir. Náà, pron. dem. Aquele, aquela, aquilo. Náà, art. O, a, os, as. Náà, adv. e conj. pré-v. Também, o mesmo.
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário). Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário). Ìjídìde, s. Revolução. Ìṣọ̀tẹ̀, s. Rebelião, insurreição. Mùsùlùmí, adj. Muçulmano, islamita, maometano, muslim. Onímàle, s. Muçulmano, islamita, maometano, muslim. Aquele que segue a religião fundada pelo profeta Maomé, o islamismo. Ìmàle, s. Islamismo. Màle, s. Malês. Àwọn, wọn, pron. Eles elas. Indicador de plural.