segunda-feira, 27 de novembro de 2017

Neoliberalismo.

Àtúnbí ti ìṣòwò ẹrú, ojú tuntun ti ìṣealáìnídé titun.
O renascimento do tráfico negreiro, a nova face do neoliberalismo.

1.  Mulheres Yazidi são escravas sexuais no Estado Islâmico.


2. Escravatura na Líbia.



3. GovernoTemer/PSDB  autoriza escravidão no Brasil




Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).


Ìtúnṣe, s. Melhoria, aperfeiçoamento.
Ìṣowó, s. Negócio, cunhagem de moeda.
Ìṣòwò, s. Comércio.
Ẹrú, s. Escravo, cativo.
Òwò ẹrú, oko ẹrú; títà àti ríra ènìyàn, s. Escravatura.
Òwò ẹrú, oko ẹrú; títà àti ríra ènìyàn, s. Escravidão. 
Ìdè, s. Ato de amarrar, escravidão. Parafuso, fivela, cinta.Gbogbo ohun èlò—láti orí páànù àti igi ìrólé títí dórí àwọn ohun ọ̀ṣọ́ àti aṣọ ojú fèrèsé, àwọn àwo ilé ìyàgbẹ́ àti ojú ibi tómi ti ń tú síni lára ní balùwẹ̀, títí kan àwọn ìdè àti ìṣó—la kó sínú àwọn ohun ìkẹ́rùsí tí a sì fi ọkọ̀ òkun kó wọn wá láti Ọsirélíà - Todos os componentes — desde a cobertura do telhado e as vigas, até a mobília e as cortinas, os vasos sanitários e os chuveiros, até mesmo parafusos e pregos — foram enviados em contêineres desde a Austrália.
Òwò ẹrú ti orí, s. Escravidão mental.
Òwò ẹrú, oko ẹrú; títà àti ríra ènìyàn, s. Escravocracia.
Olówò ẹrú, olóko ẹrú, s. Escravocrata.
Ojú tuntun, s. Nova face.
Ojú, s. Olhos, face, rosto.
Tuntun, titun, adj. Novo, fresco, recente.
Ìṣekápítálístì, ìṣeòwòèlé, kapitálísíìmù, s. Capitalismo.
Ìṣealáìnídé, s. Liberalismo.
Ìṣealáìnídé titun, s. Neoliberalismo.
, pron. rel. Que, o qual, do qual, cujo.
, conj. Se. Enquanto, ao mesmo tempo que.
, prep. Desde que.
, v. Bater com a mão ou com algo na mão, acertar o alvo.
, adv. Onde, quando.
Ti, prep. de ( indicando posse). Quando usado entre dois substantivos, usualmente é omitido. Ilé ti bàbá mi = ilé bàbá mi ( A casa do meu pai).
Ti, ti...ti, adj. Ambos... e. Ti èmi ti ìyàwó mi - ambos, eu e minha esposa.
Ti, v. Ter (verb. aux.). Arranhar. Pular.
Ti, v. interrog. Como. Ó ti jẹ́? - Como ele está.
Ti, adv. pré-v. Já. Indica uma ação realizada.
Ti, àti, conj. E.

Ti, part. pré-v. 1. Usada para indicar o tempo passado dos verbos. Èmi ti máa rìn lálé - Eu costumava caminhar à noite. 2. É usada com báwo ni - como - quando se deseja expressar sentimento e posicionada antes do verbo principal. Báwo ni àwọn ti rí? - Como eles estão?. 

Tìti, adv. Tremendamente, violentamente.
Títí, adv. Continuamente, constantemente.
Títí, prep. Até.
Tìtì, adv. Tremulamente, balançadamente.
Títì, adj. Trancado, que deve ser empurrado, fechado. 
Títì, ọ̀nàs. Via pública, rua, passagem.
Ti... ti, adj. Ambos... e. Ti èmi ti ìyàwó mi - Ambos, eu e minha esposa.
Títi-àiyé, adv. Eternamente.
Títí dé, prep. Até. (referindo-se a um local ou espaço).
Títí di, prep. Até. (referindo-se a período de tempo).
Títí  láé, títí láí, adv. Perpetuamente, para sempre, definitivamente.
Títilọ, adv. Continuadamente, assim por diante.

Ìbí, s. Nascimento. Pergunta, questão.
Àtúnwá, s. Retorno, reencarnação.
Àkúdàáyá, s. Reencarnação.
Àtúnbí, s. Regeneração, renascimento.
Àtúnhù, s. Renascer, brotar de novo.




Eu não sou da paz.

 Èmi kì í ṣe àlàáfíà
Eu não sou da paz. 


          
Àwọn gbólóhùn (frases) 

1. Mi ò ní àlàáfíà - Eu não tenho paz.

2. “Mi ò ń ṣe sùẹ̀gbẹ̀ o!” - “Eu não sou medroso!”

3. N kì í ṣe ọ̀kan lára ẹ̀yin Ẹlẹ́rìí Jèhófà - Eu não sou Testemunha de Jeová.

4. Mi ò kì í ṣe èèyàn burúkú; bẹ́ẹ̀ ni mi ò sì dára ju àwọn èèyàn tó kù lọ - Eu não sou uma pessoa má, tampouco alguém especial.

4."Èmi Jèhófà ha kọ́ ni?” - ”Não sou eu, Jeová?”

5. Ó ṣeé ṣe kó o sọ pé, ‘Àmọ́ èmi kì í ṣe wòlíì!’ - Talvez diga: ‘Mas eu não sou profeta!’

6. Èmi kì í ṣe ẹni tí ń sọ̀rọ̀ lọ́nà tí ó já geere -  Eu não sou orador fluente.

7. “Kí ló dé, ó yẹ kẹ́ ẹ ti mọ̀ pé mi ò ní báa yín dá sírú nǹkan bẹ́ẹ̀ yẹn!” - “Vamos lá, você sabe que eu não sou disso!”

Paris

Àdúgbò táwọn akúṣẹ̀ẹ́ nínú Olúìlú Paris (Fránsì).
Favela dentro de Paris (França).



A favela de Ney, nos arredores de Paris

A favela de Ney, nos arredores de Paris ERIC HADJ


Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).


Ghẹto, s. Gueto, subúrbio, favela, periferia, bairro de minorias raciais, bairro de minorias sociais, bairro judeu. 
Etílé, s. Periferia de uma cidade, arredores, circunferência, vizinhança, perímetro urbano, contorno.
Agbègbè, s. Arredores, periferia, subúrbio, cercanias. 
Ilé akúṣẹ̀ẹ́, ilé ebútú, àwọn ilé àbẹ̀rẹ̀wọ̀ táwọn èèyàn kọ́ síbi tí ìjọba ò fọwọ́ sí, àdúgbò játijàti, àgọ́ àwọn tálákà, àdúgbò táwọn akúṣẹ̀ẹ́, àwọn àdúgbò tí kò bójú mu rárá, ilé jákujàku, s. Favela. Conjunto de moradias populares que, construídas a partir da utilização de materiais diversos, se localizam, normalmente, nas encostas dos morros. Wọ́n ṣírò rẹ̀ pé àwọn tó ń gbé láwọn ilé akúṣẹ̀ẹ́ jákèjádò ayé ju bílíọ̀nù kan lọ - Estima-se que mais de 1 bilhão de pessoas em todo o mundo vivam em favelas. 
Àdúgbò táwọn akúṣẹ̀ẹ́, s. Favela. Ọ̀pọ̀ èèyàn ló jẹ́ pé àwọn ilé kẹ́jẹ́bú ni wọ́n ń gbé láwọn àdúgbò táwọn akúṣẹ̀ẹ́ pọ̀ sí táwọn ilé tó wà níbẹ̀ kò sì bójú mu rárá - Muitas têm de se contentar com moradias improvisadas em cortiços ou em favelas urbanas.
Àwọn ilé táwọn èèyàn ti pa tì, s. Casas abandonadas, prédios abandonados.
Nínú, prep. Dentro, no interior de.
, prep. No, na, em.
Parisi, Olúìlú Paris, s. Paris.
Olúìlú, s. Capital.
Ilẹ̀ Faransé Olómìnira, s. República francesa.
Fránsì, s. França.

Cotas raciais.

                                                             
Àròyé lórí àwọn ìpín tó wà láàárín àwọn ẹ̀yà.
Debate sobre cotas raciais.









Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).

Àròyé, s. Debate, discussão, controvérsia.
Àpérò, s. Consulta, conferência,  comparação, confrontação, verificação, confronto. 
Ìjọsọ̀rọ̀, àjọsọ̀rọ̀, ìsọ̀rọ̀, s. Conversação. Ìdánilẹ́kọ̀ọ́, ọ̀rọ̀ sísọ, ìsọ̀rọ̀, s. Palestra, conferência, aula. 
Ẹ̀kọ́, s. Aula, educação, instrução. 6. Yàrá ìkẹ́kọ̀ọ́: aula.
Àríyànjiyàn, s. Disputa, controvérsia.  Awuyewuye, s. Bulha, discussão, testilha, rixa, luta, desavença, combate, briga, concorrência.
Ìjíròrò orí wẹ́ẹ̀bù, s. Debate na web, discussões na web.
Lórí, lérí, prep. Sobre, em cima de. 
Ìpín, ìpífúnní, apákan, s. Divisão, partilha, porção, lote, cota.
Alápakán, s. Cotista, dono da cota.
Aláìfẹ́irúẹ̀dáọmọẹnìkéjì, s. Racista.
Ìṣẹlẹ́yàmẹ̀yà, ẹlẹyamẹya, ẹ̀mí kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà, s. Racismo. Àwọn tó ń ṣèwádìí “ò tíì ṣàwárí ohunkóhun tó bá ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ mu tó fi hàn pé òótọ́ ni ohun tí wọ́n ń sọ pé ẹ̀yà kan sàn ju ẹ̀yà míì lọ ”- Pesquisadores "nunca descobriram  nenhuma comprovação científica para apoiar as teses de superioridade racial”.
Tó wà láàárín àwọn ẹ̀yà, kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà, adj. Racial. '
Ìkórìíra tó wà láàárín àwọn ẹ̀yà, s. Ódio racial. 
Ìṣòro kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà, s. Tensão racial.
Yunifásítì, s. Universidade.
Ilé-ẹ̀kọ́ gíga, s. Escola de segundo grau.