sexta-feira, 1 de janeiro de 2021

Feliz ano novo!

Ẹ kú ọdún titun! Ọdún yìí, mo wí fún ọ, àṣẹ Orí rẹ yóò bá ọ gbé  làyè.  Síwájú sí i, gbobgo àdáwọ́lé wa ni yóò yọrí sí rere láṣẹ Olódùmarè.

Feliz Ano Novo! Este ano, eu te digo, o axé do seu Ori te acompanhará por toda a vida. Além disso, todos os nossos esforços terão sucesso na presença de Deus.




Ẹ kú ọdún Kérésìmesì! Ẹ kú iyedún! Ṣùgbọ́n,  ní orúkọ  Elédùmarè. . . jọ̀wọ́, má gbàgbé láti fún àwọn adúláwọ̀ lókun o - Feliz Natal! Feliz Ano Novo! Mas, em nome do Todo-Poderoso Deus. . . por favor, não se esqueça de fortalecer o povo preto.

Ẹ kú àlàjá ọdún!  Mo gbà gbọ́ pé ní ọdún yìí, gbobgo àdáwọ́lé wa ni yóò yọrí sí rere láṣẹ Olódùmarè - Feliz Ano Novo! Acredito que neste ano, todos os nossos esforços terão sucesso na presença de Deus.

Ẹ kú àlàjá ọdún, o̩dún àṣeyọrí àtí àláfíà ni yíò jẹ́! - Feliz ano novo, ano que será de sucesso e paz!

Ẹ kú ọdún ẹ kú ìyèdún, ọ̀pọ̀ọ rẹ̀ lẹ ó ṣe láyé! - Feliz ano novo, você fará muitas coisas boas na terra!

Ẹ kú ọdún titun! Feliz ano novo!
Ìdáhùn: Àṣẹ o. Gbobgo àdáwọ́lé wa ni yóò yọrí sí rere láṣẹ Olódùmarè - Resposta: Axé! Todos os nossos esforços terão sucesso na presença de Deus.

Lọ́dún tuntun yìí, ayọ̀ wa á kún, ọ̀nà á là fún wa. Síwájú sí i, gbobgo àdáwọ́lé wa ni yóò yọrí sí rere láṣẹ Olódùmarè - Neste novo ano a nossa alegria será plena, o caminho se abrirá para nós. Além disso, todos os nossos esforços terão sucesso na presença de Deus.

Ẹ kú ọdún ẹ kú ìyèdún! Lọ́dún yìí, ọ̀pọ̀ọ rẹ̀ lẹ ó ṣe láyé - Feliz Ano Novo! Neste ano, você fará muitas coisas boas na terra.

Ẹ kú àlàjá ọdún, o̩dún àṣeyọrí àtí àláfíà ni yíò jẹ́!
Àṣẹ Èṣù. Ọdún á y'abo fún gbogbo wa. Mo dúpẹ́ gidi gan-an ni - Axé Exu. O ano será seguro para todos nós. Muito obrigado.