Ìtàn ilẹ̀ Nàìjíríà (História da Nigéria)
Ìṣeọ̀rọ̀àsìkò (cronologia)
Ìṣíwájú ìtàn, s. Pré-História
Ayéijọ́un àti Àkókò Ojú Dúdú (Síwájú 1500), s. Os tempos antigos e medievais (pré-1500), História Antiga pré-1500.
Kùtùkùtù ìgbà òdeòní, s. Início dos tempos modernos (Período Pré-colonial 1500–1800).
Nàìjíríà Alámùúsìn, s. Nigéria colonial 1800–1960.
Ìgba Òṣèlú Àkọ́kọ́, s. Primeira República 1960–1979.
Ogun Abẹ́lé, s. Guerra civil 1967–1970
Ìgba Òṣèlú Èkejì, s. Segunda República 1979–1983
Ìgba Òṣèlú Ẹ̀kẹta, s. Terceira República 1993–1999
Ìgba Òṣèlú Ẹ̀kẹrin, s. Quarta República 1999–presente.