Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.
Ìbèèrè, àbèèrè, s. Pergunta, questão, requisição. Ìṣòro, s. Dificuldade, problema. Ọmọ-ìbílẹ̀, ẹ̀yà abínibí, onílẹ̀, ìbílẹ̀, s. Índio, nativo, aborígine, indígena. Ti ìbílẹ̀, ti ilẹ̀, ti ìlú, ti ọmọ-ìbílẹ̀, adj. Indígena, nativo, aborígene. Ilẹ̀, s. Terra, solo, chão. Bràsíl, s. Pindorama, Brasil. Mẹ́rin, num. Total de quatro. Ìṣẹ́jú, s. Minuto. Iṣoṣó, s. Gentileza, encantamento.
Ọmọbìnrin, s. Filha. Ọmọkùnrin, s. Filho. Ọmọ àgbàbọ́, s. Filho adotivo. Ọmọ àgbo, ọmọ ọwọ́, ọmọ ọmú, s. Bebê, criança. Ọmọ aládé, s. Príncipe, princesa. Ọmọ aláìloobi, ọmọ òkú, s. Órfão. Ọmọ àlè, s. Bastardo, o filho da outra.
Ọmọbíbí, s. Nascimento de uma criança. Ọmọdé, s. Criança. Ọmọ̀dọ̀, s. Criada, serviçal. Ọmọdọ́mọ, s. De criança em criança, de tempos em tempos. Ọmọ ènìà, s. Ser humano, cavalheiro. Ọmọ ẹ̀hìn, s. Discípulo, seguidor, aprendiz. Ọmọge, s. Mulher jovem, criada. Ọmọge ìbílẹ̀, ọmọ ìlú, s. Nativo da terra. Ọmọ iléwé, akẹ́kọ̀ọ́, akẹ́kọ́, ọmọ ilé-ẹ̀kọ́, ọmọ-sùkúrù, s. Aluno, estudante. Ọmọ ìlú, s. Nativo da mesma cidade, nativo da mesma região.
Ọmọ jẹ́jẹ́, s. Criança fina, gentil. Ọmọkọ́mọ, s. Qualquer criança, uma criança má. Ọmọ làlà, s. O primeiro neto. Ọmọlé, s. Grupo familiar. Ọmọlẹ́hìn, s. Seguidor. Ọmọlójú, s. Neto, menina dos olhos. Ọmọlúwàbí, s. Pessoa de caráter, cavalheiro e educado. Ọmọ ọba, s. Filho do rei, príncipe, princesa. Ọmọnìkéjì, s. Companheiro, vizinho. Ọmọ ọmọ, s. Neto. Ọmọ-ọmú, s. Criança em fase de amamentação. Ọmọpẹ́, s. Denominação de uma criança que passa dos nove meses de gestação. Ọmọṣẹ́, s. Aprendiz de trabalho. Ọmọ tuntun, s. Recém-nascido, bebê. Ọmọ wáhàrí, s. Filho de uma escrava tomada como esposa. Ọ̀mọ̀wé, s. Pessoa educada, sábia. Ọ̀mọwẹ̀, s. Nadador.