1. Hermetismo
Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.
sexta-feira, 13 de maio de 2016
Teologia
A ni ọmọlẹ́hìn Kristi.
Somos cristãos.
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário).
A, àwa, pron. Nós.
Ni, v. Ser, é.
Jẹ́, v. Ser. É mais usado para definir uma personalidade e qualidades morais de uma pessoa.
Ọmọ-ẹ̀hìn Kristi, ọmọlẹ́hìn Kristi, s. Seguidor de Cristo, cristão.
1. Ìmọ̀ Ọlọ́run ìlọ́rọ̀.
Teologia da prosperidade.
2. Ìmọ̀ Ọlọ́run dúdú.
Teologia negra.
3. Ìmọ̀ Ọlọ́run òmìnira.
Teologia da libertação.
4. Ìmọ̀ Ọlọ́run ti obìnrin.
Teologia feminista.
Somos cristãos.
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário).
A, àwa, pron. Nós.
Ni, v. Ser, é.
Jẹ́, v. Ser. É mais usado para definir uma personalidade e qualidades morais de uma pessoa.
Ọmọ-ẹ̀hìn Kristi, ọmọlẹ́hìn Kristi, s. Seguidor de Cristo, cristão.
1. Ìmọ̀ Ọlọ́run ìlọ́rọ̀.
Teologia da prosperidade.
2. Ìmọ̀ Ọlọ́run dúdú.
Teologia negra.
3. Ìmọ̀ Ọlọ́run òmìnira.
Teologia da libertação.
4. Ìmọ̀ Ọlọ́run ti obìnrin.
Teologia feminista.
Assinar:
Postagens (Atom)