Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.
ÈTÒ Ẹ̀SỌ ARA - O SISTEMA NERVOSO - ARA ENIA - CORPO HUMANO
ÈTÒ Ẹ̀SỌ ARA
O SISTEMA NERVOSO
ENIA
ÀWỌN ÈTÒ Ẹ̀YÀ-ARA
Nível de leitores
Primário, Secundário, Avançado
by Fakinlede K
VIEW AS PDF
Português
Yorùbá
Português
Yorùbá
Nervo
Ẹ̀sọ
Sistema nervoso central
Ètò ẹ̀sọ t’ogangan
Célula nervosa (neurônio)
Pádi ẹ̀sọ
Sistema nervoso periférico
Ètò ẹ̀sọ t’àgbèègbè
Cordão do nervo
Ìṣù ẹ̀sọ
Nervo espinhal
Ẹ̀sọ atopayo
Fibra nervosa
Ọ̀ran ẹ̀sọ
Coluna vertebral
Ọ̀pá ẹhìn
Raiz nervosa
Irìn ẹ̀sọ
Neurônio
Neurologia
Ẹ̀kọ́ ẹ̀sọ
canal espinhal
Ihò ọ̀pá-ẹhìn
Neurologista
Oníṣègùn ẹ̀sọ-ara
Axônio
Cérebro
Ọ̀pọlọ
Dendritos do neurônio
Irun ẹ̀sọ
Medula espinhal
ẹ̀sọ ọ̀pá-ẹhìn
Nervo motor
Ẹ̀sọ ìmira
Nervo espinhal
ẹ̀sọ atọ̀páyọ
Nervos sensoriais
Àwọn ẹ̀sọ-iyè
Neurônio motor
Pádi ẹ̀sọ-ìmira
Nervo autônomo (neurônio)
Ẹ̀sọ adáṣiṣẹ́
Neurônio motor
Pádi ẹ̀sọ-ìmira
O sistema nervoso consiste em células que comunicam informações sobre o entorno de um organismo e sobre si mesmo.
Ètò ẹ̀sọ Ara ní àwọn pádi (cell) kan tó njẹ ki ẹ̀dá-oníyè ní ìfura sí àgbèègbè rẹ
O sistema nervoso é dividido em dois sistemas principais, o sistema nervoso central (SNC) e o sistema nervoso periférico. A medula espinal e o cérebro compõem o SNC. Sua principal função é obter as informações do corpo e enviar instruções. O sistema nervoso periférico é composto de todos os nervos e da fiação. Este sistema envia as mensagens do cérebro para o resto do corpo.
A pín ètò ẹ̀sọ-ara sí ọnà méjì, ètò ẹ̀sọ t’ọgangan àti ètò ẹ̀sọ t’àgbèègbè. ẹ̀sọ ọ̀pá-ẹhìn àti ọpọlọ ló jẹ́ àpapọ ẹ̀sọ t’ọgangan. Iṣẹ́ rẹ pàtàkì ni gbígba ìhìn (information) láti ara àti láti fi àṣẹ ránṣẹ sí gbogbo ara. Èto ẹ̀sọ t’àgbèègbè ni àwọn ẹ̀sọ gbogbo tó yí inú ara káàkiri bí àwọn (net). Àwọn eléyi ni wọn ngba ìhìn (information) láti ọpọlọ tí wọn si nfi ránṣẹ sí gbogbo ara
Os nervos sensoriais enviam mensagens de partes do corpo, como pele e músculos, de volta à medula espinhal e ao cérebro.
Àwọn ẹ̀sọ-iyè ló nṣe ìránṣẹ láti gbogbo ara, bí awọ-ara àti iṣan ara, padà lọ sí ẹ̀sọ ọ̀pá ẹhìn àti ọpọlọ
Os nervos autonômicos controlam funções involuntárias ou semi-voluntárias, como freqüência cardíaca, pressão arterial, digestão, regulação da temperatura e sudorese.
Àwọn ẹ̀sọ adáṣiṣẹ́ ló nṣe olùdarí àwọn ẹya-ara tí kò sí lábẹ ìdarí wà. Àwọn nkan bí ìyási sísọ ọkàn, èéfún òpó-ẹ̀jẹ̀, dídà-onjẹ, àtọsọnà ìgbóná ara, àti ìlàágùn.
Os nervos motores enviam impulsos ou sinais do cérebro e da medula espinal para todos os músculos do corpo.
Àwọn ẹ̀sọ ìmira (mi ara: move a body part) ló nṣe ìránṣẹ láti ọpọlọ àti ẹ̀sọ ọ̀pá-ẹhìn sí gbogbo àwọn iṣan ara