Lítíréṣọ̀ áti Ìmọ̀ ọgbọ́n orí Áfíríkà.
Literatura e filosofia africana.
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário).
Áfríkà, Áfíríkà, s. África.
Ìṣe gbogbo Áfríkà, ìṣe pan-áfríkánístì, s. Pan-africanismo.
Gbogbo ọmọ Áfríkà, adj. Pan-africano.
Ọmọ-ẹ̀hìn ìṣe pan-áfríkánístì, ọmọlẹ́hìn ìṣe pan-áfríkánístì, s. Seguidor do pan-africanisno, pan-africano.
Filọ́sọ́fi, ìmòye, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, èrò àwọn ọ̀mọ̀ràn, èrò àwọn onímọ̀ ọgbọ́n òrí, s. Sabedoria, filosofia, rekhet.
Èrò ìjìnlẹ̀ tó ń fi Áfríkà bí ipò kìíní nínú ìgbésí ayé wa, s. Afrocentricidade.
Èrò ìjìnlẹ̀, s. Teoria.
Ìmọ̀ ọgbọ́n orí Ẹ́gíptì, s. Filosofia egípcia.
Filọ́sọ́fi Bàntú, s. Filosofia bantu.
Lítíréṣọ̀, s. Literatura.
Ẹ̀kọ́ fífi-òye-mọ-Ọlọ́run tó wọ́pọ̀ lápá Ìlà Oòrùn ayé, s. Misticismo Oriental.
Òun, ó, pron. pess. Ele, ela.

Pẹ̀lú, prep. Com, junto com.
Pẹ̀lú, adv. Também.
Pẹ̀lú, v. Estar em companhia de, acompanhar.
Pẹ̀lú, conj. E. Liga substantivos, mas não liga verbos.
Pẹ̀lú, adv. Também.
Pẹ̀lú, v. Estar em companhia de, acompanhar.
Pẹ̀lú, conj. E. Liga substantivos, mas não liga verbos.
Sì, ( conj. pré-v.). E, além disso, também. Liga sentenças, porém, não liga substantivos; nesse caso, usar " àti". É posicionado depois do sujeito e antes do verbo.
Ti, àti, conj. E.
Àti, Conj. E. Usada entre dois nomes, mas não liga verbos.
Òun, on, Conj. E. Geralmente usada com nomes de pessoas. Òjó on Àjàdí - Ojô e Ajadi.
Oun, ohun, s. Coisa, algo.
Oùn, ohùn, s. Voz.
Oun, ohun, s. Coisa, algo.
Oùn, ohùn, s. Voz.