segunda-feira, 15 de fevereiro de 2016

Crime organizado no Brasil



Ìwà ọ̀daràn ṣètò ní'lẹ̀ Bràsíl.
Crime organizado no Brasil.

Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).


Ṣètò, adj. Organizado.
Ìwà ọ̀daràn, s. Crime, criminalidade.
Àgbájọ, ẹgbẹ́ ìkójọ, ìtò lẹ́sẹsẹ, àjọ, s. Organização.
, prep. No, na, em.
Ilẹ̀, s. Terra, solo, chão.
Bràsíl, s. Brasil.




Yorùbá


Our Yoruba Lesson and Books We Use | DNVlogsLife | VEDA 2015 Day 1

                                                                  





Orúkọọ́ mi ni Wálé. Mo jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ ní Yunifásítì ti Texas ní Austin. Mo fẹ́ràn ilé-ìwéè mi gan-an ni nítorí pé gbogbo ohun tí ó lè mú kí ẹ̀kọ́ rọ ènìyàn lọ̀rùn ni ó wà níbẹ̀ àgàgà nínú kíláàsìì mi. 
Oríṣiríṣi nnkan ni ó wà nínú kíláàsìì mi. Láraa wọn ni àga‚ tábìlì, àwòrán‚ kọ̀npútà‚ mọ́nítọ̀‚máòsì‚ kííbọọdù‚ ìwé atúmọ̀-èdè‚ pẹ́ẹ̀nì‚ pẹ́nsùlù‚ rúlà‚ ìrésà‚ fídíò‚ síídiì‚ fáìlì‚ máàpù àgbáyé‚ ṣọ́ọ̀kì‚ pátákó-ìkọ̀wé àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ
Lẹ́yìn èyí‚ a tún lè rí àwọn nnkan mìíràn tí wọ́n mú kíláàsìì mi yàtọ̀ sí kíláàsì mìíràn ni Yunifásítì bíi ìlẹ̀kùn aláràbarà‚ fèrèsé aláràbarà‚ iná ìlẹ́tíríìkì‚ àjà‚ apẹ̀rẹ̀-ìdalẹ̀nùsí àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ
Mo fẹ́ràn ilé-ìwéè mi lọ́pọ̀lọpọ̀. Mo sì máa n fi í yangàn láàárín àwọn ọ̀rẹ́ẹ̀ mi nítorí pé náánní náànnì náánní‚ ohun a ní là á náánní bí ọmọ aṣẹ́gità ṣe n náánní èpo igi.


Religião de Orixá

Ẹ̀sìn Òrìṣà (religião de Orixá)                                          


sábado, 13 de fevereiro de 2016

Pequeno Universo

Àgbáyé kékeré.
Pequeno universo.

Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).

Kékeré, adj. Pequeno.
Àiyé, ayé, àgbáyé,  gbogbo ẹ̀dá, s. Universo.                                                             


sexta-feira, 12 de fevereiro de 2016

Videoteca

Àwọn fídíò lórí ìkànnì.
Vídeos na Web.

Àwọn = eles, elas.Indicador de plural.
Fídíò = vídeo.
Ní, L = no, na, em.
Lórí Ìkànnì = na web.
Orí Ìkànnì =  on-line, web.



https://www.google.com.br/webhp?source=search_app&gfe_rd=cr&ei=-jy-VrHKK8vM8AeF2bSADQ&gws_rd=ssl#q=video+ilha+das+flores+completo

Dicionário


Ìwé atúmọ̀ èdè (dicionário)


Resultado de imagem para dicionário yorubá



http://www.yorubadictionary.com/a.htm

https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%88d%C3%A8_(G%E1%BA%B9%CC%80%E1%BA%B9%CC%81s%C3%AC-Yor%C3%B9b%C3%A1):_B

Site

Kí ló wà lórí ìkànnì wa?
O que pode ser encontrado em nosso site?


Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).

Kí, kín = o que.

= que.
= tranquilizar-se.
Ni, L = ser, é.
= é ele.
Lo = é você.
Kí ló = o que
= estar.
Lórí, lérí = sobre, em cima de.
Ibùdó, orí ìkànnì, ojú-òpó-wẹ́ẹ̀bù = site.
Wa = nosso, nossa.



http://www.dn.pt/globo/africa/interior/reforma-agraria-no-zimbabue-corrigiu-injustica-colonial-3178275.html

https://support.mozilla.org/yo/products/webmaker/thimble