Ẹ̀rọ mọ̀nà-mọ́ná (gerador de energia)
O lè Kẹ́kọ̀ọ́ èdè yorùbá pẹ̀lú Olùkọ́ Orlandes o sì, síwájú sí i, jẹ́ kí àwọn òrìṣà darí ẹ padà sí ìlú ìbílẹ̀ rẹ. Kí èrò inú rẹ lílágbára ṣẹ, òmìnira, yan ohun tí ó tọ́ o sì di olórí rere - Aprenda yorubá com o professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.
domingo, 8 de janeiro de 2017
2017
Ẹ káàbọ̀ si ọdún Ẹgbàálémẹ́tàdínlógún (Bem-vindo a 2017)
Ẹ kú Ọdún titun! - Feliz ano novo!
Ọdún Ẹgbàálémẹ́tàdínlógún dé – Ano de 2017 está aqui.
A dúpẹ́ pé ó bá wa láyé - Somos gratos por estar vivo.
Ọlọrun á ṣe ọdún ni ọdún ayọ̀ – Deus fará ano de alegria.
Ìlú wa yi ó tòrò lágbára Èdùmàrè – Pelo poder de Deus, nosso país será pacífico.
Ẹ̀mí wa á ṣe ọ̀pọ̀ ọdún pẹ̀lú ara li le - Que você possa viver para comemorar muitos anos de boa saúde
Ẹ káàbọ̀ si ọdún Ẹgbàálémẹ́tàdínlógún – Bem-vindo a 2017.
Cuba
Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Kúbà República de Cuba
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário).
Orílẹ̀, s. Nome que denota um grupo de origem ou clã.
Orílẹ̀-èdè, s. Estado, nação.
Èdè, s. Idioma, língua, dialeto.
Olómìnira, adj. Independente.
Ilẹ̀, s. Terra, solo, chão.
Kúbà, s. Cuba.
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário).
Orílẹ̀, s. Nome que denota um grupo de origem ou clã.
Orílẹ̀-èdè, s. Estado, nação.
Èdè, s. Idioma, língua, dialeto.
Olómìnira, adj. Independente.
Ilẹ̀, s. Terra, solo, chão.
Kúbà, s. Cuba.
sábado, 7 de janeiro de 2017
Assinar:
Postagens (Atom)