domingo, 8 de janeiro de 2017

Oração

Obinrin ti ó nṣe ìbà Aṣẹ̀dá 
Uma mulher fazendo reverência ao Criador.

Obinrin ti ó́ nṣe Ì̀bà Aṣẹ̀dá - A woman paying reverence to the Creator. Courtesy: @theyorubablog

Legado

Ránti ọmọ ẹni ti iwọ nṣe.
Deixe um bom legado. 

Ránti Ọmọ Ẹni ti Iwọ Nṣe - Leave a good legacy.  Courtesy: @theyorubablog

Caçador

Ọlọ́dẹ, ọdẹ (caçador)

Ọlọ́dẹ/Ọdẹ - Hunter


Bi Ọdẹ bá ro ìṣẹ́ ro ìyà inú igbó, ti ó bá pa ẹran kòní fẹ́nì kan jẹ.
Se o Caçador pensa no sofrimento na natureza, ele não compartilharia sua morte com ninguém.

Família

Ẹbí pé jọ láti pín Ogún.
Família reunida para partilhar herança.

Ẹbí pé jọ lati pín Ogún – Family gathered to share inheritance

Trabalhador rural

Àwọn Alágbàṣe ní Oko.
Operários na fazenda.

Resultado de imagem para trabalhador rural

Muhammadu Buhari

Olóri Òṣèlù tuntun Muhammadu Buhari 
Presidente recentemente eleito Muhammadu Buhari. 

Resultado de imagem para Muhammadu Buhari.

Indisciplina

Ìgbógun ti Ìwà ìbàjẹ́. 
Guerra Contra a Indisciplina. 

Resultado de imagem para Indisciplina