sexta-feira, 9 de março de 2012

DINHEIRO

OWO TÍ MO SAN
O DINHEIRO QUE EU PAGUEI

Museu do holocausto

Ilé ìkóhun-ìṣẹ̀ǹbáyé-sí  Ìpakúpa (Museu do  holocausto).



A imagem pode conter: texto


Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).
Ibi Ìkóhun-ìṣẹ̀ǹbáyé-sí, ilé ohun láíláí, mùsíòmù, s. Museu. 
Ilé ìkóhun-ìṣẹ̀ǹbáyé-sí tó wà ní kọ́lọ́fín, s. Museu secreto.
Ìpakúpa, s. Genocídio, holocausto. Ìrònú pé ogun átọ́míìkì arunlérùnnà lè jà nígbàkigbà ń kó ìpayà bá aráyé - A preocupação sobre um possível holocausto nuclear continua a afligir a humanidade.
Agbára ìjọba aláṣẹ oníkùmọ̀, ètò ìjọba aláṣẹ oníkùmọ̀, ìjọba bóofẹ́bóokọ̀ arínilára,  s. Fascismo.
Ìmúnisìn tipátipá, ìjọba ìmúnisìn tipátipá, s. Totalitarismo (hitlerismo, fascismo, nazismo, nacional-socialismo).
Ètò ìjọba Násì, s. Nazismo.
Ẹgbẹ́ násì, s. Partido nazista.
Ẹgbẹ́ aláṣẹ bóofẹ́bóokọ̀, s. Partido de extrema direita.
Ẹgbẹ́  àwọn Òṣìṣẹ́ Sósíálístì Tọmọorílẹ̀-èdè Jẹ́mánì, s. Partido Nacional Socialista dos Trabalhadores Alemães.

Ẹgbẹ́ àwọn afáríkodoro alátakò ìjọba Násì, s. Skinheads neonazistas.
Afáríkodoro, s. Pesso acabeça raspada.
Ẹgbẹ́ ìmùlẹ̀ Ku Klux Klan, s. Ku Klux Klan.

Onípadà-sẹ́hìn, aládẹ̀hìnbọ̀, olùpadà-sẹ́hìn, konsafetifu, s. Reacionário, conservador.
Ti àdẹ̀hìnbọ̀, adj. Reacionário, conservador.
Mọniwọnba, adj. Conservador.

Ìjọba ológun, s. Governo militar.
Àgọ́ ìṣẹ́niníṣẹ̀ẹ́ Násì, s. Campo de concentração nazista.