segunda-feira, 8 de maio de 2017

Intolerância religiosa

                                                   
Ìtara aláìmòye ti ẹ̀sìn.
Intolerância religiosa.





Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).

 Ìtara aláìmòye, ìfi ori-kuku, aìmoye di nkan mu, s. Fanatismo, intolerância, zelo excessivo, beatice.
Àìkò lémí, s. Intolerância.
Ìtara, s. Zelo.
Aláìmòye, s. Pessoa sem percepção, pessoa abobalhada.
Àìmòye, s. Imprudência.
Nkan, pron. indef. Algo, alguma coisa.
Nkan, s. Coisa, algo.
Nkankan, s. Nada.
Nkan-kí-nkan, adj. Qualquer coisa.
Nkan oṣù, s. Menstruação (lit. coisas do mês).
Di, v. Tornar-se, vir a ser. Ir direto. Ensurdecer. Cultivar.
Di, prep. Até. Quando indica tempo ou período, é antecedida por títí. Mo ṣiṣẹ́ títí di agogo mẹ́rin - Eu trabalhei até as 16h. Se indica de um período para outro, é antecedida por láti. Mo sùn láti  aago kan di aago méjì lójojúmọ́ - Eu durmo de 13 h até as 14 h diariamente.
Mu, v. Beber, embeber, ensopar. Sugar, chupar, fumar. 
, adj. Sonoro, agudo, claro.
, v. Tomar, pegar coisas leves e abstratas. Capturar, agarrar. Ser severo. Ser afiado.
Oríkunkun, s. Obstinação, teimosia.
Kúkú, v. Preferir.
Kúkù, s. Mestre-cuca (do inglês cook), cozinheiro.
Olùjọ́sìn, s. Adorador, cultuador.
Olùfọkànsìn, s. Um devoto.
Ẹ̀sìn, ìsìn, s. Culto, religião.
Ti, prep. de ( indicando posse). Quando usado entre dois substantivos, usualmente é omitido. Ilé ti bàbá mi = ilé bàbá mi ( A casa do meu pai).
Ti, ti...ti, adj. Ambos... e. Ti èmi ti ìyàwó mi - ambos, eu e minha esposa.
Ti, v. Ter (verb. aux.). Arranhar. Pular. 
Ti, v. interrog. Como. Ó ti jẹ́? - Como ele está.
Ti, adv. pré-v. Já. Indica uma ação realizada.
Ti, àti, conj. E.
Ti, part. pré-v. 1. Usada para indicar o tempo passado dos verbos. Èmi ti máa rìn lálé - Eu costumava caminhar à noite. 2. É usada com báwo ni - como - quando se deseja expressar sentimento e posicionada antes do verbo principal. Báwo ni àwọn ti rí? - Como eles estão?. 

Blogues e sites


   Àwọn búlọ́ọ̀gì àti ojú-òpó-wẹ́ẹ̀bù ní èdè yorùbá.
   Blogues e sites no idioma yorubá.
      
Resultado de imagem para Blog

1. http://thonnyhawany.blogspot.com.br/search/label/%C3%80D%C3%99R%C3%80


2. http://aulasdeyoruba.blogspot.com.br/

3. http://profjosebenedito.blogspot.com.br/2011/10/licoes-de-lingua-yoruba-licao-212.html

4. https://www.hsph.harvard.edu/nutritionsource/healthy-eating-plate/translations/yoruba/


Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).


Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas.. Indicador de plural.
Búlọ́ọ̀gì, wẹ́ẹ̀bù aláfikù lémọ́lémọ́, s. Blog, blogue, diário online. blog é uma palavra que resulta da simplificação do termo weblog. Este, por sua vez, é resultante da justaposição das palavras da língua inglesa web e log. Web aparece aqui com o significado de rede (da internet) enquanto que log é utilizado para designar o registro de atividade ou desempenho regular de algo. Numa tradução livre podemos definir blog como um diário online.
Wọ inú búlọ́ọ̀gì, v.  Blogar. Ter acesso à área reservada de um site ou programa de computador através de um login, com nome de usuário e senha; fazer login, acessar, entrar.
Búlọ́ọ̀gì, wẹ́ẹ̀bù aláfikù lémọ́lémọ́, s.  Blog (diário online).
Akọbúlọ́ọ̀gì, s. Blogueiro.
Akọbúlọ́ọ̀gì, s. Bloguista.
Ibùdó, s Acampamento, local, lugar, sítio, site na internet. 
Lórí Ìkànnì, orí íńtánẹ́ẹ̀tì, s On-line, online. 
Ìkànnì, s. Site. Kí ló wà lórí ìkànnì wa? - O que pode ser encontrado em nosso site?
Ojú-òpó-wẹ́ẹ̀bù, ibiìtakùn, s. Site.
Ojú-òpó wẹ́ẹ̀bù, s. Site da web.
, prep. No, na, em. Usada para indicar o lugar em que alguma coisa está. Indica uma posição estática.
Èdè yorùbá, s. Lingua yorubá.

Julgamento de Lula

Ẹjọ́ lòdì sí Ààrẹ Lula tẹ́lẹ̀.
Processo judicial contra o ex-presidente Lula.



                                                      



Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).


Ìgbéṣẹ, ìlànà, s. Processo.
Ẹjọ́, s. Processo judicial.
Àntí, pref. Anti, contra, em oposição a. 
Mọ́, prep. Contra.
Ọ̀kánkán, prep. Contra, em oposição, em frente a. 
, prep. Contra, para, com, em, junto de.
Àntí, pref. Contra.
Aṣòdì, òṣòdì, s. Adversário, oponente.
Lòdì, adj. Contrário, adverso.
Lòdì sí, prep. Contra.
, prep. Para, em direção a. Indica movimento direcional.
Òfin, s. Lei.
Ààrẹ, s. Presidente.
Tẹ́lẹ̀, s. Ex (que deixou de ser alguma coisa). Àwọn ìpín amójútó Nàìjíríà tẹ́lẹ̀ - Antigas divisões administrativas da Nigéria.

domingo, 7 de maio de 2017

Conferência sobre Alimentação Saudável

Ìpàdé gbogbogbòò nípa oúnjẹ sí ní ìlera.                                                      
Conferência sobre Alimentação Saudável.




Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário)
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).

Ìpàdé gbogbogbòò, s. Conferência.
Gbogbo, adj. Todo, toda, todos, todas.
Nípa, nípasẹ̀, adv. Sobre, acerca de, concernente a.  
Lórí, lérí, prep. Sobre, em cima de.
Oúnjẹ, ohun-jíjẹ, s. Comida, comestíveis, alimento, iguaria, maná e manjar.
Oúnjẹ sí ní ìlera, oúnjẹ ìlera, oúnjẹ aṣaralóore, s. Alimentação saudável.
Oúnjẹ aṣaralóore, s. Alimento nutritivo.
Sí ní ìlera, ní ìlera, adj. Saudável, alimentoso, esculento, substancial, alimentício.
Àwọn, wọ́n, pron. Eles elas. Indicador de plural. 
Wọn, pron. poss. Deles, delas.
Wọn, pron. oblíquo, A eles, a elas. Possui função reflexiva e é posicionado numa frase  de pois de verbo ou proposição.
Àwo àte oúnjẹ, s. Bandeja de comida.
Àwo, s. Prato.
Àwo àte, s. Bandeja.
Oúnjẹ, ohun-jíjẹ, s. Comida, comestíveis, alimento, iguaria, maná e manjar.
Ìlera, s. Saúde.
Oúnjẹ aṣaralóore, s. Alimento nutritivo. 
Re, v. Trocar ou perder as penas. Ser bom, ser gentil.
Ṣẹ, v. Preencher, completar, tornar-se realidade. Acontecer, ocorrer.
Qúínóà, s. Quinoa.
Ògì, s. Amido de milho
Ọkà, s. Milho, comida feita com farinha de inhame ou de mandioca, misturada com água fervente, uma espécie de àmàlà. 
Àgbàdo, s. Milho. 
Ìrẹ́sì, ìrẹsì, s. Arroz. 
Ìrẹsì funfun, s. Arroz branco.
Súgà, s. Açúcar.
Búrédì funfun, s. Pão branco.
Irúgbìn wóró, s. Semente de mostarda.



Prato: alimentação saudável.

                                                                                                                                                                   
Àwo oúnjẹ ìlera.
Prato: alimentação saudável.



Yoruba_Aug2015


Portuguese Healthy Eating Plate

Àwo Oúnjẹ Ìlera (Yoruba)


Àwo àte oúnjẹ aṣaralóore la ṣẹ àgbékalè rè láti ọwọ́ àwọ́n onímò ti ilé-ìwé ètò ìlera ọ̀fẹ́ ní Havard tí a sì ṣẹ àgbéjadè rẹ̀ ní ilé-iṣẹ́ àgbéjadè ètò ìlera, èyí tó jẹ́ fún láti pe àkíyèsí wa sì oúnjẹ tó pé – yálà a bùú sínú abó tàbí sínú ike tí a fi ń gbé oúnjẹ pamọ́. Fi àpẹẹrẹ rẹ̀ kan sára fíríìjì láti máa dúró gẹ́gẹ́ bíi ape-àkíyèsí sí ìlera, àti jíjẹ́ oúnjẹ tó pé tó sì sara-lóore.
  • Mú kí oúnjẹ re kún fún ewébẹ̀ àti èèso – Ìdajì abọ́:
Lọ fún àwò lórísìírísìí, sì rántí pé ọ̀dùnkún kìí ṣẹ ewébè tí a lè kà kún gbíbe ní ìlera nítorí wọ́n ní ipa tí kò dára lórí ìtọ̀-súgà.
  • Lọ fún oúnjẹ wóóró irúgbìn kan – ó gbọ́dọ̀ jẹ́ ìdá mẹ́rin àbọ̀:
Oúnjẹ oníhóró ẹlẹ́yọ̀ – wíìtì, báálì, èèso wíìtì, qúínóà, ògì, ọkà, ìresì àti oúnjẹ tí a sè pèlú wọn, bíi oúnjẹ tí a fi àgbàdo àti ìrẹsì ṣẹ – wọ́n ní àbáyọrí díè lóri ìtò- súgà àti inslulínì ju búrédì funfun lọ, ìresì funfun àti a àwọ́n oúnjẹ irúgbìn wóró kan yókù tí a tún ṣe.
  • Oúnjẹ Amúnidàgbà – ó gbọ́dọ̀ jẹ́ ìdá mẹ́rin àbọ̀:
Ẹja, adìye, ẹ̀wà àti èèso ẹlẹ́pà bíi ẹ̀pà sísè, yíyan, kaṣú abbl ló dára, àwọn oúnjẹ ámaradàgbà míì tí a mú láti oríson mìíran tí – a lè dàpọ̀ mọ́ sàláàdì, àti tí a tún lè jẹ pèlú ewébè nínú abọ́. Jẹ ẹran níwọ̀nba, kí o sì sá fún ẹran bíi sọ́sáàjì àti bákóònù.
  • Oúnjẹ ọlọ́ràá:
Lo òróró ìsebè tó kún fún ìlera tó wà fún ìdágbásókè ara láti mú kí ara wa wà lálàáfíà bíi òróró ólívì, sóyà, àgbàdo abbl. Kí o sì sá fún àwọn òróró tí ó ń mú ní sanra tó ní àwọn ohun tí kò lè ṣara lóore. Rántí pé ọ̀rá ìwọ̀nba kò túnmọ̀ sí pé o wà ní “Ìlera Pípé”.
  • Mu omi, tíì tàbí kofí:
Sá fún àwọn ohun mímu tó dùn, dín mílíìkì òòjọ́ mímu kù sí èèkan tàbí èèmejì lójúmọ́, kí osì mu ife kékére kan lójoojúmọ́.
  • Máa wà lákínkanjú ní gbogbo ìgbà:
Àwọn àwòrán ohun pupa/ẹlẹ́jẹ̀ tó ń sáré kiri nínú àwòran àwo ìléra jẹ́ ìrántí láti máa wà ní akínkanjú àti ọ̀nà láti dín ọ̀sùwòn ìwọ̀n kù.
Kókó inú àpèjúwe oúnjẹ aṣaralóore ní láti dúró lé ìwọ̀n oúnjẹ tó pé:
  • Irúfé oúnjẹ afáralókun tó wà nínú oúnjẹ se pàtàkì ju oye oúnjẹ afáralókun tó wà nínú oúnjẹ lọ, torí àwọn oríson oúnjẹ afáralókun bíi ewébè (àti òdùnkún), èèso, oúnjẹ wóró irúgbìn kan, àti ẹ̀wà jẹ́ èyí tó ní ìlera ju àwọn yókù lọ.
  • Ó tún gba ni níyànjú pé oníbárà gbọ́dọ̀ yàgò fún àwọn ohun mímu onísúgà, èyí tó jẹ́ orísun tó tóbi jù fún ìsanra – Ó wà lórí díẹ̀ lára àwọn oúnjẹ tó ní ìdíyelé.
  • Oúnjẹ ìlera yìí náà tún gba oníbárà níyànjú láti lo òróró tó ní ìlera nínú; kò sì ní èyí tí ó pòjù lọ nínú ìwọ̀n ìtóbi tí ènìyàn gbọ́dọ̀ ní lójúmọ́ láti ara oríson ọ̀rá tó mú ìlera dání.

Awọn ofin lilo
A gba àwọn ènìyàn láyè láti lo àwọn àwòrán inú àwo oúnjẹ ìlera yìí ní ìbámu pèlú àwọn wọ̀nyí:
  • O gbọ́dọ̀ lo àwọn ìpè wọ̀nyí: “Copyright 2011 Harvard University. Fún àlàye kíkún nípa àwo oúnjẹ ìlera, jòwó wo oríson oúnjẹ amúnidàgbà, ìpín oúnjẹ amúnidàgbà, ilé-ìwé ìlera ọ̀fé, http://www.thenutritionsource.org ati Harvard Health Publications, health.harvard.edu.’’
  • Ìlò àwòrán àwo oúnjẹ amúnidàgbà kìí ṣẹ fún títà.
  • Ìlò àwòrán àwo oúnjẹ amúnidàgbà yìí gbọ́dọ̀ jé èyí tí ó tèlé gbogbo òfin tí a gbé kalẹ̀.
  • O kò lè sàtúnṣẹ/sàyípadà àwọn àwòrán/akosílẹ̀ rẹ̀ ní ọ̀nà kọnà.
  • Ilé-ìwé Harvard leè ṣẹ àgbápadà/àpèpadà àṣẹ rẹ̀ nígbàkúùgbà gẹ́gẹ́ bí ó bá ti pinu. Ní àkókò tí a bá ti ṣẹ àpèpadà ìgbàláàye náà, o gbọ́dọ̀ yọ àwòrán náà kúrò nínú ẹ̀rọ álatagbàà tàbí ibi tí gbogbo ènìyàn ti leè rí láàarín ọjọ́ márùn-ún.
  • Harvard lodi si gbogbo àpẹẹrẹ – yálà èyí tí a gbé jáde tàbí tí a fé lò-èyí tí o rò pé tàbí tó lè fa ká rò pé Harvard, ìpín oúnjẹ amúnidàgbà ti ilé-ìwé ìlera ọ̀fẹ́, tàbí orísun oúnjẹ amúnidàgbà alátagba ti buwọ́ lu ọjà, iṣẹ́, ènìyàn, ẹgbẹ́ tàbí ibi-iṣẹ́ kísé. Nítorí náà, o lè má lo orúkọ “Harvard,” ìpín ti oúnjẹ amunidagba ti ilé-ẹ̀kọ́ ìlera ọ̀fe tàbí “orísun oúnjẹ amúnidàgbà” tàbí ilé-iṣẹ́ kíṣẹ́ tó níí ṣẹ́ pèlú àtẹ ìbuwólù, ní àkọsílẹ̀, yàtọ̀ sí fún àtèjáde àwọn ìpè wọ̀nyí fún àwòrán gẹ́gẹ́ bí a ti kọ sókè yìí.
  • O lè má lo àte àwo oúnjẹ ìlera ní ọ̀nà-kọnà tó lè tàbùkù bá orúkọ Harvard.
  • Harvard lòdì sí gbogbo ìyanrantí èyíkéyìí (tí a sọ, kọ, tàbí rò) èyí tó níí ṣẹ pèlú àtẹ àwo oúnjẹ ìlera, láìsí òdiwọ̀n, ìyanranti tó lòdì bíi ti onísòwò/aláróbọ́, èyí tí a ṣẹ fún èrèdí pàtakì kan, tàbí àìnítèlé òfin náà. O gbọ́dọ̀ gbà láti san padà tàbí dìmú ohun tí kò lóró. Harvard University àti àwọn alága ìgbìmọ̀ ọ̀gá ilé-ìwé náà, àwọn aṣojù, ọmọ ẹgbẹ́, akẹ́kọ̀ọ́, òsìṣẹ́ àti agbódegbà láti lòdì sí èrí, ìbàjẹ́, ìsọnù, èyí tí a létòósí láti sanwọ́ rẹ̀, oye àti iye gbogbo nǹkan tó níí ṣẹ pèlú ìlò àwòrán àwo gbígbé ní ìlera.

Translation assistance provided by Dr. Sally N. Adebamowo

Terms of Use

The contents of this website are for educational purposes and are not intended to offer personal medical advice. You should seek the advice of your physician or other qualified health provider with any questions you may have regarding a medical condition. Never disregard professional medical advice or delay in seeking it because of something you have read on this website. The Nutrition Source does not recommend or endorse any products.

Fonte: https://www.hsph.harvard.edu/nutritionsource/healthy-eating-plate/translations/yoruba/
Fonte: https://www.hsph.harvard.edu/nutritionsource/healthy-eating-plate/translations/portuguese/


Àwo àte oúnjẹ aṣaralóore la ṣẹ àgbékalè rè láti ọwọ́ àwọ́n onímò ti ilé-ìwé ètò ìlera ọ̀fẹ́ ní Havard tí a sì ṣẹ àgbéjadè rẹ̀ ní ilé-iṣẹ́ àgbéjadè ètò ìlera, èyí tó jẹ́ fún láti pe àkíyèsí wa sì oúnjẹ tó pé – yálà a bùú sínú abó tàbí sínú ike tí a fi ń gbé oúnjẹ pamọ́. Fi àpẹẹrẹ rẹ̀ kan sára fíríìjì láti máa dúró gẹ́gẹ́ bíi ape-àkíyèsí sí ìlera, àti jíjẹ́ oúnjẹ tó pé tó sì sara-lóore.

O Prato: Alimentação Saudável, criado por especialistas em nutrição da Harvard T.H. Chan School of Public Health e editores da Harvard Health Publications, é um guia para a criação de refeições saudáveis, equilibradas – servidas em um prato ou embaladas em marmita ou caixa de almoço. Coloque uma cópia na geladeira como lembrete diário para criar refeições saudáveis e equilibradas!

1. Mú kí oúnjẹ re kún fún ewébẹ̀ àti èèso – Ìdajì abọ́:
Faça a maior parte de sua refeição com legumes e frutas – ½ do seu prato:

Lọ fún àwò lórísìírísìí, sì rántí pé ọ̀dùnkún kìí ṣẹ ewébè tí a lè kà kún gbíbe ní ìlera nítorí wọ́n ní ipa tí kò dára lórí ìtọ̀-súgà.
Selecione por cor e variedade e lembre-se que batatas não contam como vegetais no Prato:

Coma Saudável, devido a seu impacto negativo sobre o “açúcar” no sangue.

2. Lọ fún oúnjẹ wóóró irúgbìn kan – ó gbọ́dọ̀ jẹ́ ìdá mẹ́rin àbọ̀:
Escolha grãos integrais – ¼ do seu prato:

Oúnjẹ oníhóró ẹlẹ́yọ̀ – wíìtì, báálì, èèso wíìtì, qúínóà, ògì, ọkà, ìresì àti oúnjẹ tí a sè pèlú wọn, bíi oúnjẹ tí a fi àgbàdo àti ìrẹsì ṣẹ – wọ́n ní àbáyọrí díè lóri ìtò- súgà àti inslulínì ju búrédì funfun lọ, ìresì funfun àti a àwọ́n oúnjẹ irúgbìn wóró kan yókù tí a tún ṣe.

Grãos integrais e intactos – trigo, cevada, baga de trigo, quinoa, aveia, arroz integral e alimentos feitos com eles, como massa integral – têm um efeito mais suave sobre o “açúcar” no sangue e insulina do que pão branco, arroz branco, e outros grãos refinados.

3. Oúnjẹ Amúnidàgbà – ó gbọ́dọ̀ jẹ́ ìdá mẹ́rin àbọ̀:
O poder das proteínas – ¼ do seu prato:

Ẹja, adìye, ẹ̀wà àti èèso ẹlẹ́pà bíi ẹ̀pà sísè, yíyan, kaṣú abbl ló dára, àwọn oúnjẹ ámaradàgbà míì tí a mú láti oríson mìíran tí – a lè dàpọ̀ mọ́ sàláàdì, àti tí a tún lè jẹ pèlú ewébè nínú abọ́. Jẹ ẹran níwọ̀nba, kí o sì sá fún ẹran bíi sọ́sáàjì àti bákóònù.

Peixe, frango, feijão e nozes são todos fontes de proteínas saudáveis, versáteis – podem ser misturadas em saladas e acompanhar vegetais em um prato. Limite carne vermelha e evite carnes processadas, como bacon, linguiça e salsicha.

4. Oúnjẹ ọlọ́ràá:
Óleos vegetais saudáveis – com moderação:

Lo òróró ìsebè tó kún fún ìlera tó wà fún ìdágbásókè ara láti mú kí ara wa wà lálàáfíà bíi òróró ólívì, sóyà, àgbàdo abbl. Kí o sì sá fún àwọn òróró tí ó ń mú ní sanra tó ní àwọn ohun tí kò lè ṣara lóore. Rántí pé ọ̀rá ìwọ̀nba kò túnmọ̀ sí pé o wà ní “Ìlera Pípé”.

Escolha óleos vegetais saudáveis, como azeite de oliva, óleo de canola, soja, milho, girassol, amendoim, e outros, e evitar óleos parcialmente hidrogenados, que contêm gorduras trans não saudáveis. Lembre-se que baixo teor de gordura não significa “saudável”.

5. Mu omi, tíì tàbí kofí:
Beba água, chá ou café:

Sá fún àwọn ohun mímu tó dùn, dín mílíìkì òòjọ́ mímu kù sí èèkan tàbí èèmejì lójúmọ́, kí osì mu ife kékére kan lójoojúmọ́.

Evite bebidas açucaradas, limite leite e laticínios a 1-2 porções por dia, e limite suco a um copo pequeno por dia.


6. Máa wà lákínkanjú ní gbogbo ìgbà:
Mantenha-se ativo:

Àwọn àwòrán ohun pupa/ẹlẹ́jẹ̀ tó ń sáré kiri nínú àwòran àwo ìléra jẹ́ ìrántí láti máa wà ní akínkanjú àti ọ̀nà láti dín ọ̀sùwòn ìwọ̀n kù.

A figura vermelha correndo através da bandeja do Prato: Alimentação Saudável é um lembrete de que permanecer ativo também é importante para controlar o peso.


Kókó inú àpèjúwe oúnjẹ aṣaralóore ní láti dúró lé ìwọ̀n oúnjẹ tó pé:

A principal mensagem do Prato: Alimentação Saudável é concentre-se na qualidade da dieta.

* Irúfé oúnjẹ afáralókun tó wà nínú oúnjẹ se pàtàkì ju oye oúnjẹ afáralókun tó wà nínú oúnjẹ lọ, torí àwọn oríson oúnjẹ afáralókun bíi ewébè (àti òdùnkún), èèso, oúnjẹ wóró irúgbìn kan, àti ẹ̀wà jẹ́ èyí tó ní ìlera ju àwọn yókù lọ.

O tipo de carboidrato da dieta é mais importante do que a quantidade de carboidratos porque algumas fontes de carboidratos – como legumes (exceto batatas), frutas, grãos integrais e feijões-são mais saudáveis do que outros.


* Ó tún gba ni níyànjú pé oníbárà gbọ́dọ̀ yàgò fún àwọn ohun mímu onísúgà, èyí tó jẹ́ orísun tó tóbi jù fún ìsanra – Ó wà lórí díẹ̀ lára àwọn oúnjẹ tó ní ìdíyelé.

O Prato: Alimentação Saudável também aconselha os consumidores a evitarem bebidas açucaradas, uma fonte importante de calorias – geralmente com pouco valor nutricional.


* Oúnjẹ ìlera yìí náà tún gba oníbárà níyànjú láti lo òróró tó ní ìlera nínú; kò sì ní èyí tí ó pòjù lọ nínú ìwọ̀n ìtóbi tí ènìyàn gbọ́dọ̀ ní lójúmọ́ láti ara oríson ọ̀rá tó mú ìlera dání.

O Prato: Alimentação Saudável incentiva os consumidores a usarem óleos saudáveis e não define um percentual máximo de calorias que as pessoas deveriam ingerir diariamente de fontes saudáveis de gordura.

Awọn ofin lilo
Termos de Uso do Prato: Alimentação Saudável


A gba àwọn ènìyàn láyè láti lo àwọn àwòrán inú àwo oúnjẹ ìlera yìí ní ìbámu pèlú àwọn wọ̀nyí:

Autorizamos a permissão para usar a imagem do Prato: Alimentação Saudável, de acordo com os seguintes termos e condições:


* O gbọ́dọ̀ lo àwọn ìpè wọ̀nyí: “Copyright 2011 Harvard University. Fún àlàye kíkún nípa àwo oúnjẹ ìlera, jòwó wo oríson oúnjẹ amúnidàgbà, ìpín oúnjẹ amúnidàgbà, ilé-ìwé ìlera ọ̀fé, http://www.thenutritionsource.org ati Harvard Health Publications, health.harvard.edu.’’

Você deve incluir uma frase para citar os créditos: “Copyright © 2011 Harvard University Para mais informações sobre o Prato: Alimentação Saudável, consulte The Nutrition Source, Department of Nutrition, Harvard T.H. Chan School of Public Health, http://www.thenutritionsource.org and Harvard Health Publications, health.harvard.edu”.

*Ìlò àwòrán àwo oúnjẹ amúnidàgbà kìí ṣẹ fún títà.

Seu uso do Prato: Alimentação Saudável deve ser de natureza não comercial.

* Ìlò àwòrán àwo oúnjẹ amúnidàgbà yìí gbọ́dọ̀ jé èyí tí ó tèlé gbogbo òfin tí a gbé kalẹ̀.
Seu uso do Prato: Alimentação Saudável deve estar em conformidade com todas as leis aplicáveis.

* O kò lè sàtúnṣẹ/sàyípadà àwọn àwòrán/akosílẹ̀ rẹ̀ ní ọ̀nà kọnà.
Você não pode fazer qualquer modificação na imagem ou no texto.

* Ilé-ìwé Harvard leè ṣẹ àgbápadà/àpèpadà àṣẹ rẹ̀ nígbàkúùgbà gẹ́gẹ́ bí ó bá ti pinu. Ní àkókò tí a bá ti ṣẹ àpèpadà ìgbàláàye náà, o gbọ́dọ̀ yọ àwòrán náà kúrò nínú ẹ̀rọ álatagbàà tàbí ibi tí gbogbo ènìyàn ti leè rí láàarín ọjọ́ márùn-ún.

Harvard pode revogar essa permissão a qualquer momento, a seu critério exclusivo. Caso a permissão seja revogada, você deve remover a imagem de qualquer site ou espaço público em um prazo máximo de cinco dias úteis.

* Harvard lodi si gbogbo àpẹẹrẹ – yálà èyí tí a gbé jáde tàbí tí a fé lò-èyí tí o rò pé tàbí tó lè fa ká rò pé Harvard, ìpín oúnjẹ amúnidàgbà ti ilé-ìwé ìlera ọ̀fẹ́, tàbí orísun oúnjẹ amúnidàgbà alátagba ti buwọ́ lu ọjà, iṣẹ́, ènìyàn, ẹgbẹ́ tàbí ibi-iṣẹ́ kísé. Nítorí náà, o lè má lo orúkọ “Harvard,” ìpín ti oúnjẹ amunidagba ti ilé-ẹ̀kọ́ ìlera ọ̀fe tàbí “orísun oúnjẹ amúnidàgbà” tàbí ilé-iṣẹ́ kíṣẹ́ tó níí ṣẹ́ pèlú àtẹ ìbuwólù, ní àkọsílẹ̀, yàtọ̀ sí fún àtèjáde àwọn ìpè wọ̀nyí fún àwòrán gẹ́gẹ́ bí a ti kọ sókè yìí.

Harvard estritamente proíbe qualquer indicação, explícita ou implícita, que sugira ou possa fazer com que outros acreditem que Harvard, o Departamento de Nutrição da Harvard T.H. Chan School of Public Health, ou o site Nutrition Source endossou quaisquer mercadorias, serviços, indivíduo, grupo, ou organização de qualquer tipo. Portanto, você não pode usar os nomes “Harvard”, “Departamento de Nutrição da Escola de Saúde Pública de Harvard”, ou “Fonte de Informação em Nutrição”, ou quaisquer marcas de propriedade de Harvard em conexão com o Prato: Alimentação Saudável, sem autorização prévia, por escrito, exceto para reproduzir a frase com os créditos específicos para a imagem, tal como estabelecido acima.

* O lè má lo àte àwo oúnjẹ ìlera ní ọ̀nà-kọnà tó lè tàbùkù bá orúkọ Harvard.

Você não pode usar o Prato: Alimentação Saudável de qualquer forma que possa lesar a reputação de Harvard.

* Harvard lòdì sí gbogbo ìyanrantí èyíkéyìí (tí a sọ, kọ, tàbí rò) èyí tó níí ṣẹ pèlú àtẹ àwo oúnjẹ ìlera, láìsí òdiwọ̀n, ìyanranti tó lòdì bíi ti onísòwò/aláróbọ́, èyí tí a ṣẹ fún èrèdí pàtakì kan, tàbí àìnítèlé òfin náà. O gbọ́dọ̀ gbà láti san padà tàbí dìmú ohun tí kò lóró. Harvard University àti àwọn alága ìgbìmọ̀ ọ̀gá ilé-ìwé náà, àwọn aṣojù, ọmọ ẹgbẹ́, akẹ́kọ̀ọ́, òsìṣẹ́ àti agbódegbà láti lòdì sí èrí, ìbàjẹ́, ìsọnù, èyí tí a létòósí láti sanwọ́ rẹ̀, oye àti iye gbogbo nǹkan tó níí ṣẹ pèlú ìlò àwòrán àwo gbígbé ní ìlera.

Harvard isenta de todas as garantias, de qualquer tipo (expressa, implícita ou de outra forma), o uso do Prato: Alimentação Saudável, incluindo, sem limitação, quaisquer garantias implícitas na comercialização, adequação a uma finalidade específica e não violação. Você concorda em indenizar e isentar a Universidade de Harvard e os membros do seu Conselho Diretor, diretores, membros do corpo docente, alunos, funcionários e agentes de e contra todas as reivindicações, danos, perdas, responsabilidades, custos e despesas de qualquer natureza decorrentes ou relacionadas ao seu uso do Prato: Alimentação Saudável.



Translation assistance provided by Dr. Sally N. Adebamowo

Terms of Use

The contents of this website are for educational purposes and are not intended to offer personal medical advice. You should seek the advice of your physician or other qualified health provider with any questions you may have regarding a medical condition. Never disregard professional medical advice or delay in seeking it because of something you have read on this website. The Nutrition Source does not recommend or endorse any products.

Parlamento Pan-Africano


Iléaṣòfin Gbogbo Ọmọ Áfríkà.
Parlamento Pan-Africano.

Abusos da Lava Jato

 Ọ̀rọ sísọ ti Oyè ìjìnlẹ̀ Luigi Ferrajoli ní Ilé Aṣòfin Olúìlú Rómù - pẹ̀lú àkọlékè ní èdè Pọrtugí.

 Palestra do PH.D Luigi Ferrajoli no Parlamento de Roma - com legenda em português.
                                                         



Jurista de reputação mundial, condena abusos da Lava Jato

Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário). 

Ìbá-sọ̀rọ, ọ̀rọ sísọ, s.  Discurso, sermão, palestra.
Ti, prep. De ( indicando posse). Quando usado entre dois substantivos, usualmente é omitido. Ilé ti bàbá mi = ilé bàbá mi ( A casa do meu pai).
Olùkọ́, s. Professor.
Oyè ìjìnlẹ̀, s.  PH.D, Philosophiæ Doctor, Doutor de Filosofia.
Dókítà, s. Doutor.
Ilé Aṣòfin, s. Parlamento. 
Kọ́ngrésì Onítọmọorílẹ̀-èdè, s. Congresso nacional.
Aṣòfin, s. Legislador.
Ìlú, s. Cidade, terra, região, país.
Olúìlú, s. Capital.
Rómù, Róòmù, s. Roma.
Ítálì, Itálíà, s. Itália.
, prep. No, na, em.
Pẹ̀lú, prep. Com, junto com.
Pẹ̀lú, adv. Também.
Pẹ̀lú, v. Estar em companhia de, acompanhar.
Pẹ̀lú, conj. E. Liga substantivos, mas não liga verbos.
Àkọlékè, s. Inscrição; letreiro, legenda. Explicação junto a uma fotografia, desenho, planta, carta geográfica etc. Tradução, em vernáculo, que acompanha as imagens de um filme falado em idioma estrangeiro.
Àkọlé, s. Subscrição, endereço de uma correspondência.
Èdè Pọtogí, èdè Pọrtugí, s. Língua portuguesa.