Lílọ gbàwòsàn (consulta médica).
Déètì (data): 24/03
Àkókò (horário): 9: 45
Àdírẹ́ẹ̀sì (endereço):
Àwọn àyẹ̀wò déédéé lọ́dọ̀ dókítà (exames médicos regulares)
Àyẹ̀wò ẹṣẹ́ tí ń pèsè omi àtọ̀ nínú ara (exame de próstata):
Déètì (data): 26/03
Àkókò (horário): 11: 00
Àdírẹ́ẹ̀sì (endereço): Ilé ìwòsàn Òṣìṣẹ́ Ìjọba Ìpínlẹ̀ ( Hospital do Servidor Público Estadual).
Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò, àkójọ ọ̀rọ̀ tí ò ń lò lójoojúmọ́, àwọn àkànlò ọ̀rọ̀, àwọn àkànlò èdè, ọ̀rọ̀ tó máa ń sọ, àkànlò èdè lọ́nà tó gún régé (vocabulário).
Nwọ́n, pron. pess. Eles, elas. Expressa uma ação que não é creditada a nenhuma pessoa em particular.
Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas. É também usado como partícula para formar o plural do substantivo; neste caso, é posicionado antes do substantivo.
Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.
Wọn, pron. poss. Deles, delas.
Onímọ̀ nípa ẹ̀yà ara tí ó ní í ṣe pẹ̀lú ìtọ̀, s. Urologista.
Ẹ̀kọ́ nípa iṣẹ́ ìtọ́jú àìsàn inú àwọn ẹ̀yà ara àfitọ̀, s. Urologia.
Ẹ̀ka Ìtọ́jú Àìsàn Inú Àwọn Ẹ̀yà Ara Àfitọ̀ ní ilé ìwòsàn kan, s. Setor de urologia de um hospital.
Àrùn jẹjẹrẹ inú okùn àpòòtọ̀ ọkùnrin, s. Câncer de próstata.
Àyẹ̀wò ẹṣẹ́ tí ń pèsè omi àtọ̀ nínú ara, s. Exame de próstata
Ẹṣẹ́ tí ń pèsè omi àtọ̀ nínú ara, s. Próstada.
Àrùn jẹjẹrẹ inú ẹ̀yà ara tí ń pèsè omi tí ń gbé sẹ́ẹ̀lì àtọ̀, s. Câncer de próstata.