Ilé-ẹjọ́ Gígajùlọ (Supremo Tribunal Federal)
Fonte: https://www.youtube.com/watch?v=Hl9jAsjWbzQ
Ẹ kọ́ èdè Yorùbá lọ́dọ̀ Olùkọ́ Orlandes àti pé, láfikún sí i, ẹ jẹ́ kí àwọn Òrìṣà tọ́ ọ padà síbi tí ẹ ti wá. Ẹ jẹ́ kí èrò inú rẹ lágbára, kí ó lómìnira, kí ẹ ṣe àwọn àṣàyàn tó dára, kí ẹ sì di olórí rere - Aprenda o idioma yorubá com o Professor Orlandes e, além disso, deixe os orixás guiá-lo de volta à origem. Que vossa mente seja forte, livre, faça boas escolhas e se torne olórí rere.
Àwọn ìwé ìwádìí (livros de pesquisa, fontes de pesquisa):
1. Orísun ìsọfúnni: Ìkànnì https://afrikhepri.org/pt/le-site-de-mpumalanga/
Fonte de informação: Site https://afrikhepri.org/pt/le-site-de-mpumalanga/
2. Gẹ́gẹ́ bí ìwé gbédègbẹ́yọ̀ Brockhaus lédè Jámánì ṣe sọ, ìgbà kan wà tó jẹ́ àṣà àwọn alákòóso tí wọ́n jẹ́ ọmọ ìjọ Pùròtẹ́sítáǹtì láti máa lo àmì tí wọ́n fi oòrùn àti lẹ́tà Hébérù mẹ́rin tó dúró fún orúkọ Ọlọ́run ṣe ọ̀ṣọ́ sí - Segundo a enciclopédia alemã Brockhaus, houve época em que era costume os príncipes protestantes usarem a insígnia de um sol estilizado junto com o Tetragrama.
3. Àwọn ìwé tó o lè lọ wò - Livros que você pode procurar, lista de referências para consultar.
4. Àkójọ àwọn ìwé táa ti wádìí - Lista de livros pesquisados, bibliografia.
5. Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações.
6. Ìwé kan tá a ṣèwádìí nínú ẹ̀ sọ pé - Uma obra de referência diz que.
7. Ìwé atúmọ̀ èdè orí íńtánẹ́ẹ̀tì "Glosbe" tá a ṣèwádìí nínú ẹ̀ sọ pé - O Dicionário online Glosbe diz que.
8. Wikipéédíà (ìwé-ìmọ̀ ọ̀fẹ́) tá a ṣèwádìí nínú ẹ̀ sọ pé - A wikipédia que pesquisamos diz que.
9. Gẹ́gẹ́ bí Ìwé atúmọ̀ èdè orí íńtánẹ́ẹ̀tì "Glosbe"ṣe sọ - De acordo com o dicionário "Glosbe".
10. Òǹkọ̀wé nì, Síkírù Sàlámì (King), sọ pé - O autor, Síkírù Sàlámì (King), diz que.
11. Gẹ́gẹ́ bí olùkọ̀wé náà Síkírù Sàlámì (King) ṣe sọ - De acordo com o escritor Síkírù Sàlámì (King), segundo o escritor Síkírù Sàlámì (King).
12. Àkọsílẹ̀ orísun àwọn ìwé pàtàkì tí a lo nínú ìwádìí - Bibliografia das principais fontes usadas na pesquisa.
13. Àkójọ àwọn ìwé kan tí wọ́n lò fún ìwádìí - Uma lista de livros usados para pesquisa, bibliografia.
14. Ẹgbẹ́ Àwọn Olùkọ́ni Sáyẹ́ǹsì àti Ìmọ̀ iṣẹ́ ẹ̀rọ ní Èdè Yorùbá - Associação de Educadores de Ciência e Tecnologia na Língua Yorùbá (Association of Educators of Science and Technology in Yorùbá Language).
15. Ọ̀pọ̀ àwọn ọlọ́gbọ́nlóye ti ń ṣèwádìí látinú àwọn ìwé wọ̀nyí - Muitos intelectuais estão pesquisando esses livros.
16. Àkọsílẹ̀ jàn-ànràn jan-anran lórí ìwádìí tó ṣe nípa - Extensa documentação de sua pesquisa sobre.
17. Àkójọ àwọn ìwé tí ń wádìí - Lista de livros de pesquisa.
18. Ìwé ìtọ́ka tí ó dájú tí ó sì ṣeé gbẹ́mìí lé kan - Texto de referência, seguro e autêntico.
19. Ìkànnì orí Íńtánẹ́ẹ̀tì ìtọ́ka tí ó dájú tí ó sì ṣeé gbẹ́mìí lé kan - Um site de referência, seguro e autêntico.
https://languagedrops.com/word/en/yoruba/english/translate/%E1%BA%B9%CC%80r%E1%BB%8D_%C3%ACl%E1%BB%8D%E1%B9%A3%E1%BB%8D/
https://pt.glosbe.com/pt/yo/Sites%20de%20refer%C3%AAncia
20. Ìwádìí yìí nínú èdè tí wọ́n fi kọ àpilẹ̀kọ náà - Pesquisa no idioma em que o artigo foi escrito.
21. Ìwé ìtọ́ka - Livro de referência.
22. Ìwé-ìléwọ́ ẹ̀kọ́ ìmọ̀-jìnlẹ̀ àti ìmọ̀-ẹ̀rọ́ - Manual de ciência e tecnologia.
23. Onímọ̀ ọgbọ́n orí ọmọ ilẹ̀ Bràsíl, Huberto Rohden wá sọ pé - O filósofo brasileiro Huberto Rohden afirma que.
24. Tí o kò bá tíì wo ìkànnì https://afrikhepri.org/pt/le-site-de-mpumalanga/, a rọ̀ ẹ́ pé kó o lọ wo ohun tó wà níbẹ̀ - Se você não viu o site https://afrikhepri.org/pt/le-site-de-mpumalanga/, pedimos que você vá e veja o que está lá.
25. Tí o kò bá tíì wo ìkànnì jw.org, a rọ̀ ẹ́ pé kó o lọ wo ohun tó wà níbẹ̀ - Se ainda não conhece esse site, faça uma visita!
26. Ìkànnì https://solven.com.br tá a ṣèwádìí nínú ẹ̀ sọ pé - O site https://solven.com.br que pesquisamos diz que:
27. Ìkànnì tá a ṣèwádìí nínú ẹ̀ sọ pé - O site que pesquisamos diz que: