Ẹ̀kọ́ nípa iṣẹ́ ìtọ́jú àìsàn ọkàn-àyà (cardiologia)
Aláìsàn: Màríà Kristina
Déètì (data): 29/04
Àkókò (horário): 11: 00
Àdírẹ́ẹ̀sì (endereço): ilé ìwòsàn kan tí wọ́n ń pè ní "Santa Márcia", àdúgbò (Jabaquara).
Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò, àkójọ ọ̀rọ̀ tí ò ń lò lójoojúmọ́, àwọn àkànlò ọ̀rọ̀, àwọn àkànlò èdè, ọ̀rọ̀ tó máa ń sọ, àkànlò èdè lọ́nà tó gún régé (vocabulário).
Nwọ́n, pron. pess. Eles, elas. Expressa uma ação que não é creditada a nenhuma pessoa em particular.
Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas. É também usado como partícula para formar o plural do substantivo; neste caso, é posicionado antes do substantivo.
Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.
Wọn, pron. poss. Deles, delas.
Aláìsàn, s. Paciente.
Ilé ìwòsàn kan tí wọ́n ń pè ní "Santa Márcia", s. Uma clínica médica chamada "Santa Márcia).
Àdúgbò. s. Bairro.