Àwọn òpó mẹ́rin tíọ́rì ìwéwèé ọlọ́gbọ́n-nínú.
Quatro pilares da teoria do design inteligente (TDI):
1. Ìlọ́júpọ̀ tí kò ṣeé dín kù - Complexidade irredutível.
2. Àwọn ìsọfúnni tí ìṣètò apilẹ̀ abùdá ní nínú - Informações contidas no código genético.
3. Ìṣètò kan tó pé pérépéré tá a lè rí nínú àgbáyé. Ìtẹ̀sí àràmàǹdà kan tó há sáàárín ìlànà náà, bóyá nínú ìgbésẹ̀ agbára àmọ̀ọ́mọ̀-ṣe-nǹkan, tí ó sì jẹ́ olóye, tí ó mú kí àgbáálá ayé ṣe gẹ́ẹ́ ní ìmúrasílẹ̀ fún dídé wa - Um ajuste fino (arranjo perfeito) que podemos observar no universo. Uma misteriosa propensão que se esconde dentro do processo, talvez na ação de um poder inteligente e proposital que ajustou com precisão o universo em preparação da nossa chegada.
4. Agbára láti mọ ohun tó ń bọ̀ wá ṣẹlẹ̀ - Antevidência.
Ronú nípa èyí ná (pense nisso): Ǹjẹ́ tíọ́rì ìwéwèé ọlọ́gbọ́n-nínú ni ayédèrú sáyẹ́ǹsì? - Será que a teoria design inteligente é pseudociência?
Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações:
https://www.tdibrasil.com/#
Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas. É também usado como partícula para formar o plural do substantivo; neste caso, é posicionado antes do substantivo.
Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.
Wọn, pron. poss. Deles, delas.
Opó, s. Viúva.
Òpò, s. Preparação.
Ópò, orópò, s. Pequeno quarto de provisões.
Ópò, órópò, órúpò, s. Local no palácio do rei onde é dado audiência, um banco de terra utilizado para dormir.
Òpó-eku, s. Rastro de rato.
Tíọ́rì ìwéwèé onílàákàyè, tíọ́rì ìwéwèé ọlọ́gbọ́n-nínú, s. Teoria do design inteligente (TDI).
Ìlọ́júpọ̀ tí kò ṣeé dín kù, s. Complexidade irredutível, complexidade impossível de ser simplificada.
Àwọn ìsọfúnni tí ìṣètò apilẹ̀ abùdá ní nínú, s. Informações contidas no código genético.
Àkójọ òfin apilẹ̀ àbùdá, s. Código genético.
Tí ó díjú, adj. Complexo, complicado.
Àyípadà tó dára jù lọ nínú ayé àtọ̀run, s. A melhor mudança do universo.
Àgbáálá ayé tó wà létòlétò, s. Universo ordenado.
Ẹlẹ́dàá ọlọ́gbọ́n-lóye kan tó dá ayé òun ọ̀run àtàwọn ohun abẹ̀mí, s. Um criador inteligente que criou o universo e os seres vivos.
Ẹlẹ́dàá ayé òun ọ̀run, s. Criador do universo.
Iṣẹ́ ọwọ́ afinúṣọgbọ́n Oníṣẹ́-ọnà tó ṣe gbogbo ẹ̀ pátá tó sì tún fòfin tá á jẹ́ kí wọ́n lè máa síṣẹ́ pa pọ̀ lélẹ̀, s. Trabalho de um Projetista inteligente que criou tudo isso e estabeleceu as leis que mantêm a coesão e a harmonia.
Afinúṣọgbọ́n Oníṣẹ́-ọnà, s. Projetista inteligente.
Ìgbésẹ̀ agbára àmọ̀ọ́mọ̀-ṣe-nǹkan, tí ó sì jẹ́ olóye, tí ó mú kí àgbáálá ayé ṣe gẹ́ẹ́ ní ìmúrasílẹ̀ fún dídé wa, s. Ação de um poder inteligente e proposital que ajustou com precisão o Universo em preparação da nossa chegada.
Ìtẹ̀sí àràmàǹdà kan, s. Uma tendência misteriosa.
Agbára láti mọ ohun tó ń bọ̀ wá ṣẹlẹ̀, s. Antevidênciaa. Capacidade de saber o que vem a seguir.
Tó, v. Bastar, ser o bastante, ser o suficiente. Ser igual a, equivaler.
Tó, adj. Suficiente, bastante.Tó, pron. rel. Que. Contração de tí ó. A partícula ó é sempre usada se tí for seguida por um verbo. Antes de pronome e substantivo, ela não é usada. Ọkùnrin tó pè mí ẹ̀gbọ́n mi - O homem que me chamou é meu irmão. Kí nìdí tó fi jẹ́ pé Nóà tó gbé ayé ní nǹkan bí ẹgbẹ̀rún márùn-ún [5,000] ọdún sẹ́yìn ni Minnamaria, akẹ́kọ̀ọ́ tí kò tíì pé ọmọ ogún ọdún yìí kọ lẹ́tà tiẹ̀ sí? - Por que Minnamaria, uma estudante adolescente, escreveu sua carta a Noé, homem que viveu há uns 5.000 anos? Ọkùnrin àtobìnrin tó gbé ayé ṣáájú Kristi - Homens e mulheres que viveram antes de Cristo
Tó, tóó, adv. pré-v. Antes de. É antecedido por kí. Kí òun tó lọ, ó sọ̀rọ̀ pẹ̀lú mi - Antes de ele ir, eu conversei com ele.
Tó wà nínú, adj. Que está dentro.
Wà, v. Ser, haver, existir, estar.
Wà, V. Cavar. Remar, dirigir. Abraçar, prender, apertar . Monopolizar.
Wà, àwa, pron. pess. Você.
Wa, pron. oblíquo. Nos, conosco. Possui função reflexiva e é posicionado depois de verbo e preposição.
Wa, pron. poss. Nosso, nossa.
Inú, s. Estômago, ventre, interior, interno, no íntimo de.