Ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ nípa ètò iṣan ara ohun ọ̀gbìn.
Neurobiologia vegetal.
Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações:
https://www.scielo.br/j/rieb/a/HbkRMdc7hkqxh45YLMW5YBj/?format=pdf#:~:text=A%20neurobiologia%20das%20plantas%20(plant,afetam%20todo%20o%20corpo%20vegetal.
Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas. É também usado como partícula para formar o plural do substantivo; neste caso, é posicionado antes do substantivo.
Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.
Wọn, pron. poss. Deles, delas.
Òróró ewébẹ̀, s. Òleo vegetal.
Àwọn èròjà aláwọ̀ tó wà nínú àwọn ohun ọ̀gbìn, s. Pigmentos vegetais.
Ìwàláàyè ohun ọ̀gbìn, s. Vida vegetal.
Ètò iṣan ara, s. Sistema nervoso.
Ètò iṣan ìmọ̀lára, s. Sistema sensorial.
Ètò ìgbékalẹ̀ ọpọlọ, s. Estrutura cerebral.
Àwọn ohun ọ̀gbìn, s. Plantas.
Nípa, nípasẹ̀, adv. Sobre, acerca de, concernente a.
Kọjá, prep. Sobre, além de.
Ní orí, lórí, lérí, prep. Sobre, em cima de, cerca de, acerca de, a respeito de.
Lórísórí, prep. Em, por, ao. sobre.
Sórí, prep. Para cima de.
Nípati, prep. Conforme.
Lókè, ní òkè, prep. Acima, no alto de.