terça-feira, 24 de julho de 2018

Filosofia africana

Ìmọ̀ ọgbọ́n orí Áfríkà (filosofia africana)                                             

Estudos Africanos : Katúscia Ribeiro e Aza Njeri - Programa Ciência & Letras






.
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).

Áfríkà, Áfíríkà, s. África.
Ìṣe gbogbo Áfríkà, ìṣe pan-áfríkánístì, s. Pan-africanismo.
Gbogbo ọmọ Áfríkà, adj. Pan-africano.
Ọmọ-ẹ̀hìn ìṣe pan-áfríkánístì, ọmọlẹ́hìn ìṣe pan-áfríkánístì, s. Seguidor do pan-africanisno, pan-africano. 
Filọ́sọ́fi, ìmòye, ìmọ̀ ọgbọ́n orí, èrò àwọn ọ̀mọ̀ràn, èrò àwọn onímọ̀ ọgbọ́n òrí, s. Sabedoria, filosofia, rekhet. 
Ẹ̀kọ́ tó ń mọyì Áfríkà bí ìtọ́kasí, ìṣeọ̀rọ̀ tó ń mọyì Áfríkà bí ìtọ́kasí, s. Afrocentricidade.
Ìmọ̀ ọgbọ́n orí Ẹ́gíptì, s. Filosofia egípcia.
Filọ́sọ́fi Bàntú, s. Filosofia bantu.
Filọ́sọ́fi Híńdù, s. Filosofia hindu.
Ẹ̀kọ́ èrò orí Kọnfukiọsi, s. Filosofia de Confúcio.
Ìṣe kọnfukiọsi, s. Confucionismo.  
Táò, s. Tao.
Ìsìn Táò, s. Taoísmo.
Ìsìn Búdà, s. Budismo.
Ìsìn Híńdù, ẹ̀sìn-ìn Híndù, s. Hinduísmo
Ìsìláàmù, ìmàle, s. Islamismo.
Ìsìn kèfèrí titun, s. Neopaganismo, wicca. 
Ìsìn Jaini, s. Jainismo
Ìsìn àwọn Júù, s. Judaísmo
Ìsìn Sikh, s. Siquismo.
Ṣintó, ẹ̀sìn ìbílẹ̀ Jèpánù, s. Xintoísmo.
Ìmọ̀ ọgbọ́n orí àwọn Gíríìkì, s. Filosofia grega.
Ẹ̀kọ́ Sítọ́ìkì, s. Estoicismo.
Ìmọ̀ ọgbọ́n orí àwọn kèfèrí, s. Filosofia dos pagãos.
Ìmọ̀ ọgbọ́n orí àwọn Alárìíwísí, s. Filosofia cínica.
Ẹ̀kọ́ ọgbọ́n orí táwọn tí kò gba Ọlọ́run gbọ́, s. A filosofia daqueles que não acreditam em Deus.
Ẹ̀kọ́ èrò orí Plato, s. Filosofia de Platão.
Ẹ̀kọ́ èrò orí Aristotle, s. Filosofia de Aristóteles.
Ẹ̀kọ́ fífi-òye-mọ-Ọlọ́run tó wọ́pọ̀ lápá Ìlà Oòrùn ayé, s. Misticismo oriental.
Ìmọ̀ ọgbọ́n orí àwọn Hélénì, s. Filosofia helenística.
Ẹ̀mí kóníkálukú máa ṣe ohun tó tọ́ lójú ẹ̀, s. Relativismo.
Ìmọ̀ ọgbọ́n orí ayé, s. Filosofia do mundo.
Èrò tó ta ko ẹ̀kọ́ Mẹ́talọ́kan bọ inú Bíbélì, s. Filosofia antitrinitária,  teoria que contradiz a doutrina da Trindade.
Irú ọ̀nà ìgbésí ayé, s. Filosofia de vida.
Ìmòye èdè, s. Filosofia da linguagem.
Ìmòye ẹ̀mí, s. Filosofia da mente.
Ìmòye ẹ̀sìn, s. Filosofia da religião.
Ìmòye  olóṣèlú, s. Filosofia política.  
Ọ̀rọ̀-ìjìnlẹ̀, s. Epistemologia. 
Ọgbọ́n, s. Lógica.
Ìmòye ọ̀rọ̀-òkòwò, s. Filosofia da economia.
Ìmòye ẹ̀kọ́, s. Filosofia da educação.
Ìmòye ìtàn, s. Filosofia da história.
Ìmòye sáyẹ́nsì àwùjọ, s. Filosofia da ciência social.
Ìmòye ìfẹ́, s. Filosofia do amor.
Ìmòye ọ̀rọ̀-ìlòfẹ́, s. Filosofia da sexualidade.
Ọ̀rọ̀ àdánidá, s. Metafísica.
Aṣeláàkàyè, s. Racionalismo.
Ìṣeìrírí, s. Empirismo.
Ìṣeàgbéwò, s. Criticismo.
Ìwà ti ẹ̀mí kúántù, s. Espiritualidade quântica.
Ìran nípa Àgbáyé, wíwò nípa àgbáyé, s. Visão de mundo.
Ohun tó jẹ́ èrò, s. Ponto de vista.
Wíwò ayé, wiwò nípa ayé, wiwò nípa ayé náà, s. Cosmovisão.
Ọ̀rọ̀-ìgbéayé, ìwádìí nípa àwọn ohun tó wà lójú ọ̀run, s. Cosmologia. 
Ìwàwíwù, s. Ética.
Ọ̀rọ̀-ìwàwíwù, s. Metaética.
Ọ̀rọ̀-ẹwà, s. Estética.
Ìṣeìyèméjì, s. Ceticismo.
Ìṣe ohun ti ẹ̀mí, s. Espiritualismo.
Ẹ̀mí pé nǹkan ṣì máa dára, s. Idealismo, espírito de otimismo.

Ìmòye alátúwò, s. Filosofia analítica.
Ọ̀rọ̀àbá, èrò-ọ̀rọ̀, s. Ideologia. Sistema organizado e fechado de ideias que serve de base a uma luta política. 
Ìmúnisìn tipátipá, ìjọba ìmúnisìn tipátipá, s.  Totalitarismo.
Ìṣekọ́múnístì, ètò ìjọba Kọ́múníìsì, s. Comunismo.
Ìṣesósíálístì, ìjọba àjùmọ̀ní, s. Socialismo.
Manifẹ́stò Kómúnístì, Manifẹ́stò Ẹgbẹ́ Kómúnístì, s. Manifesto Comunista. 
Ìṣekápítálístì, kapitálísíìmù, ìṣeòwòèlé, s. Capitalismo.
Ìṣealáìnídé, s. Liberalismo.
Ìṣealainide titun, s. Neoliberalismo.
Èrò-ọ̀rọ̀ òkòwò, s. Ideologia econômica.
Èrò-ọ̀rọ̀ olóṣèlú, s. Ideologia política.
Ìṣeọ̀rọ̀àwùjọ, s. Sociologia.
Ìṣeàìlólórí, s. Anarquismo.
Ìṣesósíálístì ti ọ̀rọ̀ lásán àròsọ, s. Socialismo utópico.
Ìjọba àjùmọ̀ṣe, s. Democracia.
Ìjọba ológun, s. Ditadura militar, governo militar.
Ìṣesósíálístì ti sáyẹ́nsì, s. Socialismo científico.
Ìṣeohunayé ti ìtàn, s. Materialismo histórico.

Ìfẹ́ ọrọ̀ àlùmọ́ọ́nì,  ìfẹ́ ohun ìní tara, s. Materialismo. Kí ni Ìfẹ́ Ọrọ̀ Àlùmọ́ọ́nì? - O que é materialismo?
Ìjídìde proletárì, s. Revolução proletária.

Ìjọba Násì, s. Nazismo.
Ẹgbẹ́ àwọn Òṣìṣẹ́ Sósíálístì Tọmọorílẹ̀-èdè Jẹ́mánì, s. Partido Nacional Socialista dos Trabalhadores Alemães.
Ìjọba Aláṣẹ Oníkùmọ̀, s. Fascismo.
Nípa ará ìlúdídi ará ìlú, àyèọmọìlú, s. Cidadania.
Ọmọ ìlú, ará ìlú, ọlọ̀tọ̀, onílú, s.  Cidadão.

Ìṣẹlẹ́yàmẹ̀yà, kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà, s. Racismo
Ìwà ipá, s. Violência.
Ìwà àìgba èrò ẹlòmíì, s. Intolerância.
Onípadà-sẹ́hìn, aládẹ̀hìnbọ̀, olùpadà-sẹ́hìn, konsafetifu, s. Reacionário, conservador.
Ti àdẹ̀hìnbọ̀, adj. Reacionário, conservador.
Mọniwọnba, adj. Conservador.
Ìṣekọ́múnístì ti àwọn àkókò ìjímìjí, ìṣekọ́múnístì nígbà láéláé, ìṣekọ́múnístì àkọ́kọ́bẹ̀rẹ̀, s. Comunismo primitivo.
Ìfiniṣẹrú, s. Escravidão.

Ètò sísan ìṣákọ́lẹ̀, s. Sistema feudal.
Ìjùmọ̀sọ̀rọ̀, s. Diálogo.
Àròyé, s. Debate, discussão, controvérsia.
Ẹ̀ka ẹ̀kọ́ ilé-ìwé, s. Matéria, disciplina escolar.
Èlò, s. Matéria, utensílio.
Físíksì, s. Física. Àwọn òfin tó ń ṣàkóso gbogbo agbára tó gbé ilé ayé àti ìsálú ọ̀run ró, èyí tó jẹ́ pé àwọn onímọ̀ sáyẹ́ǹsì ṣì ń ṣèwádìí nípa rẹ̀ - As leis físicas que governam a matéria e a energia, leis que os cientistas ainda estudam.
Ti ìwà rere, ti ìwà ọmọlúàbí, adj. Moral.
Ẹ̀kọ́ ìwá rere, s. Moral.
Aláìgbọlọ́rungbọ́, s. Ateu.
Àìgbọlọ́rungbọ́, s. Ateísmo. 
Agbátẹrù ìgbàgbọ́ Ọlọ́run-kò-ṣeé-mọ̀, s. Agnosticismo.
Àwọn tó gbà gbọ́ pé Ọlọ́run kò ṣeé mọ̀, s. Agnósticos.

Onígbàgbọ́ Ọlọ́run-kò-ṣeé-mọ̀, s. Agnóstico. 
Ìlànà lílekoko, s. Metodologia. 
Àlàkalẹ̀, s. Esboço.


Ìṣeàrówà ti Jẹ́mánì, s. Idealismo alemão.













Nenhum comentário:

Postar um comentário