segunda-feira, 13 de novembro de 2023

Kilombo da nega

 Abúlé àdádó obìnrin aláwọ̀ dúdú.

Kilombo da nega. 

Abúlé ìkọ̀kọ̀ obìnrin aláwọ̀ dúdú.

Kilombo da nega.

 Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações:

https://web.facebook.com/cmpayaaasantewaa?locale=pt_BR

Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò (vocabulário), àwọn ọ̀rọ̀ tá a sábà máa ń sọ ( palavras comuns), àwọn ọ̀rọ̀ tá a sábà máa ń lò (palavras que usamos frequentemente), àkójọ ọ̀rọ̀ tá à ń lò lójoojúmọ́ (vocabulário do dia a dia), àlàyé ọ̀rọ̀, àlàyé àwọn ọ̀rọ̀ (glossário), àkójọ ọ̀rọ̀ (glossário, lista de palavras), àkójọ ọ̀rọ̀ púpọ̀ lágbárí (uma grande lista de palavras na cabeça), àkópọ̀ wóróhùn ọ̀rọ̀ dídára tí o mọ̀ (uma coleção de boas palavras que você conhece)


Nwọ́n, pron. pess. Eles, elas. Expressa uma ação que não é creditada a nenhuma pessoa em particular.

Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas. É também usado como partícula para formar o plural do substantivo; neste caso, é posicionado antes do substantivo.

Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.

Wọn, pron. poss. Deles, delas.

Ìkọ̀kọ̀, s. Privacidade, segredo.

Àdádó, ìdádó, s. Ermo, local solitário.

Abúlé tó wà ní àdádó, s. Aldeia isolada.

Àwùjọ tó wà ní ìkọ̀kọ̀, s. Sociedade secreta.

Abúlé àdádó obìnrin aláwọ̀ dúdú, s. Kilombo da nega. 

Abúlé kan tó jẹ́ ibi ìsádi àwọn ẹrú tẹ́lẹ̀, s. Uma aldeia que é local de refúgio de ex-escravos.  Abúlé àwọn èèyàn dúdú tá a lè forí pa mọ́ sí, tó jẹ́ ibi ààbò tá a lè sá sí tí ewu ìfiniṣẹrú  ò ti lè wu wá, s. Aldeia de negros que podemos nos esconder, um refúgio que pode nos manter protegidos contra o perigo da escravidão. 

Abúlé, ìletò, s. Aldeia. 

Abúlé, s. Vila, casas.

Ìletò, s. Vila, vilarejo.

Abúlé ìkọ̀kọ̀, s. Aldeia secreta. 

Abúlé àdádó, s. Aldeia isolada

Ibùgbé, s. Casa, habitação, acomodação.

Ibùgbé àrèmábọ̀, s. Assentamento permanente.

Ìbùdó, s. Acampamento.

Àgọ́, s. Acampamento, abrigo, pavilhão, barraca.

Àdúgbò kan tó dà bí àdádó, s. Uma comunidade que parece isolada (kibutz).

Ibi ìtẹ̀dó, s. Kibutz.

Abúlé kárí ayé kan, s. Uma aldeia global.

Abúlé ìkọ̀kọ̀ kan tí ó wà ní ìpínlẹ̀ Bahia ní orílẹ̀-èdè Bràsíl tí àwọn àtọmọdọ́mọ àwọn ẹ̀yà yorùbá ń gbé ibẹ̀, s. Um quilombo no estado da Bahia no Brasil habitado por descendentes das tribos Yorubá. O rei de Ifé, cidade que é berço da etnia iorubá na Nigéria, entregou o primeiro título de reconhecimento a um território quilombola (Quilombo Quingoma) no Brasil, neste domingo 19/03/2023. A cerimônia foi na comunidade Quingoma, em Lauro de Freitas, Região Metropolitana de Salvador.

Àjùmọ̀gbé, s. Ato de viver junto.

Àjùmọ̀ṣe, àjùmòṣepọ̀, s. Ação conjunta, parceria.

Àjùmọ̀ṣiṣẹ́, s. Trabalho conjunto.

Àmì ìṣàpẹẹrẹ Agbára Aláwọ̀ Dúdú, s. Símbolo do Poder Negro.

Obìnrin aláwọ̀ dúdú, s. Mulher negra

Aláwọ̀ dúdú, s. Preto.

Áfríkà, Áfíríkà, s. África.

Ìṣe gbogbo Áfríkà, ìṣe pan-áfríkánístì, s. Pan-africanismo.

Gbogbo ọmọ Áfríkà, adj. Pan-africano.

Ọmọ-ẹ̀hìn ìṣe pan-áfríkánístì, ọmọlẹ́hìn ìṣe pan-áfríkánístì, s. Seguidor do pan-africanisno, pan-africano. 

Ẹgbẹ́ àwùjọ tí ìlà ìran jẹ́ ti ìyá, àwùjọ tí ìlà ìran jẹ́ ti ìyá, s. Sociedade matrilinear, grupo social cuja linha de descendência é a da mãe. 

Ètò ẹgbẹ́ òun ọ̀gbà kan ínú èyí tí ìyá ńlá ń ṣe bíi aṣáájú ìsìn, olùkọ́ni àti onídàájọ́ nínú ìdílé rẹ̀, s. Um sistema social em que a matriarca atua como líder religiosa, instrutora e juíza dentro de sua família, sistema matriarcal. 

Ètò ẹgbẹ́ òun ọ̀gbà kan nínú èyí ìdílé ìyá ńlá tó dàbíi Ìjọba kékeré kan, tí ìyá ńlá ń ṣe bíi aṣáájú ìsìn, olùkọ́ni àti onídàájọ́, s. Um sistema social em que a família matriarcal é como um pequeno reino, onde a matriarca atua como líder religiosa, instrutora e juíza, sistema matriarcal.

Ẹgbẹ́ pan-áfríkánístì tó máa ń jà fún ẹgbẹ́ àwùjọ tí ìlà ìran jẹ́ ti ìyá, s. Coletivo matriarcal pan-Africanista, grupo pan-africanista que luta por uma sociedade matriarcal.

Ìṣeọmọorílẹ̀-èdè aláwọ̀dúdú, s. Nacionalismo negro. 

 di aṣeọmọorílẹ̀-èdè aláwọ̀dúdú àti aṣe pan-áfríkánístì, adj. Que se tornou um nacionalista negro e um ativista pan-africanista.




Nenhum comentário:

Postar um comentário