Sáyẹ́nsì ( ciência)
1 - Ìtòràwọ̀, s. Astronomia.
2 - Òfurufú, ojú òfurufú, inú òfurufú, s. Espaço sideral.
3 - Àgbáyé, s. Mundo, universo.
4 - Físíksìoníràwọ, s. Astrofísica.
5 - Atòràwọ̀, s. Astrônomo.
6 - Tẹ́lískópù, agbéwọ̀ọ́kán, s. Telescópio.
7 - Tẹ́lískópù òfurufú, ibi-ìṣàkíyèsí òfurufú, s. Telescópio espacial.
8 - Tẹ́lískópù Òfurufú Hubble, agbéwọ̀ọ́kán Òfurufú Hubble, s. Telescópio espacial Hubble.
9 - Ọkọ̀-àlọbọ̀ Òfurufú, s. Ônibus espacial.
10 - Ibùdó Òfurufú Akáríayé, s. Estação espacial
internacional.
11 - Ilé-iṣẹ́ Ìmójútó Ìrìnlófurufú àti Òfurufú Orílẹ̀-èdè Amẹ́rííà, s. NASA, Administração Nacional da Aeronáutica e do Espaço.
12 = Ìṣàgbéṣe òfurufú ọmọorílẹ̀-èdè Nàìjíríà, s. Agência espacial nigeriana.
13 -Ìràwọ̀, s. Estrela.
14 - Spẹ́ktróskópì, s. Espectroscopia.
15 - Òrùn, Òòrùn, s. Sol.
16 - Sístẹ̀mù Òrùn, Ọ̀nà ètò tòòrùn, Ètò òòrùn, s. Sisema solar.
Àwọn Plánẹ̀tì (os planetas).
1 - Mẹ́rkúríù, s. Mercúrio.
2- Àgùàlà, s. Vênus.
3 -Ilẹ̀-ayé, s. Terra.
4-Mársì, s. Marte.
5-Júpítérì, s. Júpiter.
6-Sátúrnù, s. Saturno.
7- Úránù, s. Urano. 8- Nẹ́ptúnù, s. Netuno.
17 - Òṣùpá, s. Lua.
18 - Ìwákiri lófurufú, s. Exploração espacial.
19 - Ìfòlókè òfurufú ènìyàn, s. Voos Tripulados.
20 - Ástẹ́rọ́ìdì, s. Asteróide.
21 - Arìnlófurufú, s. Astronauta.
22 - Ìrìnlófurufú, s. Aeronáutica.