segunda-feira, 10 de março de 2025

 Ìgbìmọ̀ àwọn ẹ̀yà Bushmen ilẹ̀ Gúúsù Áfríkà

Conselho San da África do Sul (South African San Council) 

Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações:

https://www.sancouncilsa.org/projects-6

https://www.oxfordreference.com/display/10.1093/oi/authority.20110803100028707

https://www.youtube.com/watch?v=HYTzJjuWsV8


Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò, àkójọ ọ̀rọ̀ tí ò ń lò lójoojúmọ́, àwọn àkànlò ọ̀rọ̀, àwọn àkànlò èdè, ọ̀rọ̀ tó máa ń sọ, àkànlò èdè lọ́nà tó gún régé (vocabulário).


Nwọ́n, pron. pess. Eles, elas. Expressa uma ação que não é creditada a nenhuma pessoa em particular.

Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas. É também usado como partícula para formar o plural do substantivo; neste caso, é posicionado antes do substantivo.

Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.

Wọn, pron. poss. Deles, delas.

Ẹ̀yà ìran, s. Etnia, grupo étnico.

Àwọn èèyàn Bushmen, s. Povo San,  povo Bosquímano.

Àwọn ẹ̀yà Bushmen, s. Tribos bosquímanas.

Ìmọ̀ràn, s. Conselho.

Ìgbìmọ̀, s. Concílio, comissão, junta.

Ìgbìmọ̀ àpapọ̀, s. Conselho geral.

Ẹgbẹ́ olùdarí, s. Comitê de direção, grupo de direção. 

Ìgbìmọ̀ olùdarí, s. Conselho de Administração.

Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Gúúsù Áfríkà, s. 
República da África do Sul.

Gúúsù Áfríkà, ilẹ̀ Gúúsù Áfríkà, s. África do Sul.

Orílẹ̀-èdè Olómìnira, s. Republica.
Ìpínlẹ̀, orílẹ̀-èdè, s. Estado.
Ìpínlẹ̀, s. Fronteira, demarcação, limite entre duas cidades, Estado ( SP, RJ).
Orílẹ̀, s. Nome que denota um grupo de origem ou clã.
Orílẹ̀-èdè, s. Estado, nação.
Èdè, s. Idioma, língua, dialeto.
Olómìnira, adj. Independente.
Ilẹ̀, s. Terra, solo, chão. 
Gúúsù, s. Sul. 
Áfríkà, s. África.