Diálogo em yorubá
K: Túnjí, báwo ni nǹkan?
(Túnjí, como vão as coisas?)
T: Dáadáa ni. Jọ̀wọ́ má bínú.
(Bem. Por favor, não me aborreça)
... K: Níbo l´o lọ lálẹ́ àná. Mo wá sí ilé ẹ lẹ́ẹ̀mejì lálẹ́ àná.
(Aonde você foi ontem à noite? Eu estive em sua casa duas vezes ontem à noite)
T: Mo gbọ́ bẹ́ẹ̀. Mo lọ rí ọmọ kíláàsì mi kan ni.
(Eu ouvi isso. Eu fui ver minha colega de classe)
K: Ki l´orúkọ ẹ̀?
(Qual é o nome dela?
T: Kimberly. (Kimberly)
K: Ọmọ ìlú ibo ni?
(Qual é a nacionalidade dela?)
T: Ọmọ ìlú Amẹ́ríkà ni, ṣùgbọ́n ó jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ ní yunifásítì ti Ìbàdàn nísisìyí. Àwọn ẹbi ẹ̀ ń gbé ní New York.
(Ela é cidadã norte americana, mas ela tornou-se aluna da universidade de Ibadan agora. Seus familiares moram em New York).
K: Ṣé a lè jìjọ lọ kí i lọ́la?
(Será que podemos ir juntos visitá-la amanhã? )
T: Bóyá.
(Talvez).

Nenhum comentário:
Postar um comentário