sábado, 12 de março de 2016

Geologia histórica

Òṣùnwọ̀n àsìkò ìṣeọ̀rọ̀oríilẹ̀ (Escala de tempo geológico)



Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).


Ìṣeọ̀rọ̀oríilẹ̀ onítàn: geologia histórica.
Òṣùnwọ̀n àsìkò ìṣeọ̀rọ̀oríilẹ̀‎: escala de tempo geológico
Ìgbà iwájú Kámbríà: pré-Cambriano 
Ìgbàrún Ìgbéyọsáyé: ‎fanerozóico.
Ìṣíwájú ìtàn: pré-História.
Ìṣeọ̀rọ̀oríilẹ̀: geologia.
Ìṣeọ̀rọ̀ọmọnìyàn, ìṣeọ̀rọ̀ayéijọ́un: arqueologia.
Ìṣeọ̀rọ̀àsìkòoríilẹ̀: geocronologia. 
Ẹ̀rúndún: milênio.
Kàlẹ́ndà: calendário.
Ìṣeọ̀rọ̀àsìkò: cronologia.
Àsíkò Ìgbéàtijọ́: ‎paleozóico.
Ìgbà Dẹfoníà: devoniano.‎ 
Ìgbà Eléèédú‎: carbonífero. 
Ìgbà Kámbríà: cambriano.‎ 
Ìgbà Ọ̀rdòfísíà‎: ordoviciano 
Ìgbà Pẹ́rmíà: permiano.‎
Ìgbà Sílúríà‎: siluriano.
Ìgbà Tríásíkì: triásico.
Ìgbà Jùrásíkì: jurássico.
Ìgbà Ẹlẹ́fun, Ìgbà Ẹfun: cretáceo.
Ìbíniàtijọ́: paleogeno.
Ìbíniọ̀tun: neogeno.






Nenhum comentário:

Postar um comentário