domingo, 16 de julho de 2017

Ferramentas

Àwọn irinṣẹ́ (ferramentas)




Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).


Irin tí wọ́n fi ń fà jáde ìṣó, s. Pé-de-cabra.
Irin kan tí wọ́n fi ń ṣí ilẹ̀kùn, s. Alavanca.
Irin kọdọrọ, s. Esquadro.
Okùn ìwọ̀n, s. Prumo.
Ẹfun láti fi fa ìlà, s. Giz de linha.
Àáké tí wọ́n fi ń bó èèpo igi, s. Machado. 
Àáké, s. Enxó O enxó (do latim asciola) é um instrumento composto por um cabo curto e uma chapa de aço cortante. É usado por carpinteiros e tanoeiros para desbastar a madeira.
Ayùn, s. Serrote, serra.
Òòlù onírins. Martelo
Òòlù, s. Martelo.
Òòlù onígi, s. Malho. Grande martelo, de cabeça pesada, sem unhas nem orelhas, próprio para bater o ferro e que, para mais fácil manejo, se pega com ambas as mãos.
Ohun tí wọ́n fi ń gbẹ́ nǹkan, s. Formões.
Irin tí wọ́n fi ń lu ihò sára igi, irin tí yóò máa fi okùn ọrun yí bírí láti fi lu ihò sára igi, s.  Arco de pua artesanal.
Àtè, s. cola.
Ìṣó, s. Prego.
Ìgbálẹ̀ kékeré,  ṣọ́bìrì kékeré, s. Chave de fenda.
Kọ́kọ́rọ́, s. Chave.
Dòjé, s. Foice.
Ọkọ́, s. Enxada, estribo.
Ìfági, s. Plana.
Ìfá, s. Ferramenta com dois cabos usada para escavar a polpa de cabaça verde.
Ìdè, s. Ato de amarrar, escravidão. Parafuso, fivela, cinta.
Èlò táa fi ń dáhò sí nǹkan, s. Furadeira.
Mítà, s. Metro.
Ọ̀pá ìdíwọ̀n díwọ̀n igun mẹ́rẹ̀ẹ̀rin ilẹ̀ ayé, s. Régua, medida, bitola.
Ọ̀pá òṣùnwọ̀n, s. Vara que serve para medir.
Rúlà olóròó, s. Régua vertical.
Ìfàlà, s. Régua.

Nenhum comentário:

Postar um comentário