sábado, 30 de dezembro de 2017

Perguntas

Nígbàmíràn olùkọ́ mi máa ńdáhùn ìbéèrè mi.
  Em outros tempos, meu professor costumava responder a minha pergunta.

 Resultado de imagem para professor

Ìwọ̀n ìfúnpá rẹ ńkọ́? - Como vai sua pressão arterial?
Báwo ni ọ̀rọ̀ tí mo fẹ́ sọ ṣe máa rí lára ẹni tí mò ń bá sọ̀rọ̀? - Como vai afetar a pessoa com quem estou conversando?
 Como vai reagir se alguém quiser fazer sexo com você?
Kí lo máa ṣe bí ẹnì kan bá ní kó o jẹ́ kẹ́ ẹ jọ ní ìbálòpọ̀? - Como vai reagir se alguém quiser fazer sexo com você?
Bá a bá yọwọ́ tèmi, ṣé o lè dá tọ́jú àwọn ọmọ ni? - Como vai sustentar os filhos sem mim?
Ìpinnu wo làwọn ọmọ ní láti ṣe, báwo ni ìpinnu yẹn á sì ṣe kan àwọn ẹlòmíì? - Que decisão os filhos precisam tomar, e como isso vai afetar outras pessoas?
Bó bá rí bẹ́ẹ̀, báwo nìyẹn á ṣe ṣẹlẹ̀? - Em caso afirmativo, como isso vai acontecer?

“Tọ́mọkùnrin mi ò bá lè ronú débi tó fi yẹ kó mọ̀ pé ó yẹ kí yàrá òun máa mọ́ tónítóní, báwo ló ṣe máa lè tọ́jú ilé tó bá bẹ̀rẹ̀ sí í dá gbé?” - “Se meu filho não consegue nem sequer manter seu quarto limpo, como ele vai conseguir cuidar de uma casa?”
Irú èèyàn wo ló máa jẹ́, kí ló máa fi ìgbésí ayé rẹ̀ ṣe, ìyẹn ohun tó máa nífẹ̀ẹ́ sí, iṣẹ́ tó máa ṣe nígbèésí ayé àti ohun tó máa gbé ṣe láyé? - Como ele vai ser, o que fará na vida, que profissão escolherá, quais serão os seus interesses e realizações?
Báwo ni Ọlọ́run ṣe fẹ́ tún ayé yìí ṣe? - Como Deus vai mudar o mundo para melhor?
Àmọ́, báwo lo ṣe lè mọ̀ bóyá o ti tó ẹni tó lè lọ máa dá gbé? - Mas como você vai saber se está realmente pronto para sair de casa?
Báwo ni wàá ṣe máa gbọ́ bùkátà ìdílé rẹ tó o bá pa dà sílé? - Como você vai conseguir sustentar a família se voltar para casa?
Báwo ni Ọlọ́run ṣe máa mú ohun tí ìyà tó ń jẹ aráyé ti fà kúrò? - Como Deus vai desfazer os efeitos do sofrimento humano?
Báwo lohun tí Ọlọ́run ní lọ́kàn ṣe máa ṣẹ? - Como Deus vai cumprir seu propósito?
Báwo lọ̀rọ̀ tí mo fẹ́ sọ lẹ́yìn ọlọ́rọ̀ yìí ṣe máa kan ojú táwọn èèyàn á máa fi wò mí? - Como isso vai afetar minha reputação?’
Kí lẹ ó máa wá fi àkókò yín ṣe lẹ́yìn tẹ́ ẹ bá parí iléèwé? - Mas como você vai usar seu tempo depois de se formar?
Báwo ni Ọlọ́run ṣe máa ṣe é? - Como Deus vai fazer isso?
Báwo ni Ọlọ́run ṣe máa yanjú àwọn ìṣòro yìí? - Como Deus vai solucioná-los?
Báwo ló ṣe máa ṣe é? - Como ele vai fazer isso?
Ṣé á mú u dání dáadáa àbí á kàn jù ú sílẹ̀? - Como ele vai lidar com o coração: com ternura ou o deixará cair no chão?
Ojú wo ló yẹ kí arákùnrin náà fi wo ọ̀rọ̀ ọ̀hún? - Como esse irmão vai encarar isso?
Ken, tó ń ṣiṣẹ́ olùkọ́ ní Ọsirélíà béèrè pé: “Báwo làwọn olùkọ́ wa ṣe máa kọ́ ọmọ ọdún mẹ́sàn-án tó jẹ́ pé àwọn òbí rẹ̀ gan-an ló kọ́ ọ ní bí wọ́n ṣe ń lo oògùn olóró, tóun náà sì ti wá di ìjìmì sínú rẹ̀?” - Ken, professor da Austrália, perguntou: “Como o professor vai lidar com uma criança de nove anos que aprendeu a usar drogas com os pais e agora está viciada?”
Nígbà tí mo kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀, mi ò lè pè ju ẹyọ ọ̀rọ̀ kan ṣoṣo lẹ́ẹ̀kan, bí mo ṣe ń ṣe é rèé: ‘[Mí sínú, gbé e mì, gùnfẹ̀] Ṣé [mí sínú, gbé e mì, gùnfẹ̀] àlááfíà [mí sínú, gbé e mì, gùnfẹ̀] ni?’ - De início, só conseguia pronunciar uma palavra por vez, assim: ‘[Inalar, engolir, arrotar] Como [inalar, engolir, arrotar] vai [inalar, engolir, arrotar] você?’
Àìlèsọ pàtó nípa irú àìsàn tó ń ṣeni àti bí a ó ṣe tọ́jú wọ́n gbé àwọn ìbéèrè tí kò ṣeé yẹ̀ sílẹ̀ dìde pé: Yóò ti pẹ́ tó tí èyí yóò fi máa bá a lọ? - Visto que muitas doenças e tratamentos são imprevisíveis, inevitavelmente surgem perguntas como: Quanto tempo isso vai continuar?
Àmọ́ báwo ni èyí yóò ṣe ṣẹlẹ̀, ìgbà wo sì ni? - Mas como e quando isso vai acontecer?
Báwo ni obìnrin náà ṣe máa rí oúnjẹ fún un, nígbà tó jẹ́ pé aláìní lòun fúnra rẹ̀? - Como é que ela vai me dar alimento, sendo tão pobre?
Báwo la ṣe mọ̀ pé lóòótọ́ làwọn òkú máa jíǹde? - Como sabemos que a ressurreição vai realmente acontecer?
Ẹ kọ nọ́ńbà síwájú àwọn ìdí tó wà nísàlẹ̀ yìí, kẹ́ ẹ bẹ̀rẹ̀ látorí èyí tẹ́ ẹ rò pé ó ṣe pàtàkì sí ọmọ yín jù? - Como você acha que ela vai numerar os fatores abaixo em ordem de importância?

Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).


Nígbàmíràn, nígbàni, adv. Algumas vezes, num tempo, em outros tempos.
Bàbá, baba, s. Pai, papai, mestre.
Olùkọ́, s. Professor.
Mi, pron. poss. Meu, minha.
Yóò, adv. pré. v. Indicador de futuro numa frase afirmativa. Em outras palavras, emprega-se o futuro do presente para expressar uma ação que será executada no futuro. Outros indicadores de futuro: yóó, ó, á, máa, fẹ́.
Máa, part. v. Usada como outra opção para marcar o tempo futuro do verbo, admitindo o pronome pessoal de uma sílaba.
Máa, v. aux. Indica uma ação habitual, costumeira.
Máa ń, a máa, adv. pré v. Ter costume de, estar acostumado, ter maneira de (fazer algo). Emprega-se o presente do indicativo para expressar uma ação constante ou habitual.
Máa, maa, obs. : Colocado antes do verbo, dá um sentido polido a uma ordem.
Dáhùn, v. Responder.
Ìdáhùn, s. Resposta, réplica.
Ìbèèrè, àbèèrè, s. Pergunta, questão, requisição.
Ń, v. Estar. Indicador de  gerúndio.
Ń, adv. pré-verbal. O prefixo "ń" no verbo indica não só uma ideia presente como uma ação que esteja ocorrendo, em desenvolvimento (gerúndio). Pela sua função, é equivalente ao verbo auxiliar estar em português.
L', pref. No.
L, pref. Forma modificada da palavra ní quando seguida de palavra iniciada por vogal diferente de i.
, prep. Contração da preposição ní e substantivo. Quando a vogal inicial do substantivo não é i, a consoante n da preposição se transforma em l, e a vogal i toma forma de vogal do substantivo posterior. Mas se a vogal do substantivo é i, ela é eliminada. Ní àná ( l'ánàá ). Ní ilé (ní'lé)
, part. enfática. Usada na construção de frases, quando o verbo tiver dois objetos, o segundo objeto é precedido por " ní".
, prep. No, na, em. Usada para indicar o lugar em que alguma coisa está. Indica uma posição estática.
, v. Ter, possuir, dizer.Transportar carga em um barco ou navio. Ocupar, obter, pegar.
Ni, v. Ser, é.
, pron. dem. Aquele, aquela. Requer alongamento da vogal final da palavra que o antecede somente na fala. Ex.: Fìlà ( a ) nì = aquele chapéu.





Nenhum comentário:

Postar um comentário