Ìṣeọ̀rọ̀àwùjọ (Sociologia).
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário).
Ìfẹ́ ọrọ̀ àlùmọ́ọ́nì, ìfẹ́ ohun ìní tara, s. Materialismo. Kí ni Ìfẹ́ Ọrọ̀ Àlùmọ́ọ́nì? - O que é materialismo?
Ìṣeohunayé, s. Materialismo.
Ìṣe ohun ti ẹ̀mí, s. Espiritualismo.
Ẹ̀mí pé nǹkan ṣì máa dára, s. Idealismo, espírito de otimismo.
Manifẹ́stò Kómúnístì, Manifẹ́stò Ẹgbẹ́ Kómúnístì, s. Manifesto Comunista.
Ìjùmọ̀sọ̀rọ̀, s. Diálogo.
Àròyé, s. Debate, discussão, controvérsia.
Ẹ̀ka ẹ̀kọ́ ilé-ìwé, s. Matéria, disciplina escolar.
Èlò, s. Matéria, utensílio.
Físíksì, s. Física. Àwọn òfin tó ń ṣàkóso gbogbo agbára tó gbé ilé ayé àti ìsálú ọ̀run ró, èyí tó jẹ́ pé àwọn onímọ̀ sáyẹ́ǹsì ṣì ń ṣèwádìí nípa rẹ̀ - As leis físicas que governam a matéria e a energia, leis que os cientistas ainda estudam.
Ìṣekọ́múnístì ti àwọn àkókò ìjímìjí, ìṣekọ́múnístì nígbà láéláé, ìṣekọ́múnístì àkọ́kọ́bẹ̀rẹ̀, s. Comunismo primitivo.
Ìfiniṣẹrú, s. Escravidão.
Ètò sísan ìṣákọ́lẹ̀, s. Sistema feudal.
Ìṣekápítálístì, ìṣeòwòèlé, s. Capitalismo.Ìṣesósíálístì, ìjọba àjùmọ̀ní, s. Socialismo.
Ìṣekọ́múnístì, ètò ìjọba Kọ́múníìsì, kapitálísíìmù, s. Comunismo.
Nenhum comentário:
Postar um comentário