sexta-feira, 24 de agosto de 2018

Salário mínimo

Owó iṣẹ́ tí ó kéré jù lọ. 
Salário mínimo. 



Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).


Owó ọ̀yà òṣìṣẹ́, s. Salário do assalariado.
Owó oṣù, owó ọ̀yà, owó iṣẹ́, s. Salário.
Owó ojúmọ́, s. Salário de um dia, dinheiro do dia
Owó rẹpẹtẹ lá á sì máa wọlé fún mi, s. Salário melhor.
Owó iṣẹ́ wákàtí kan, s. Salário de uma hora de trabalho.
Owó iṣẹ́ alágbàṣe fọ́dún kan, s. Salário de um ano de um trabalhador comum.
Owó ọ̀sẹ̀ kan, s.  Salário de uma semana.
Owó ọ̀yà pípé, s. Salário perfeito.
Owó iṣẹ́ téèyàn á fi ṣe fún nǹkan bí ìṣẹ́jú márùndínláàádọ́ta ṣe, s. Salário de 45 minutos.
Owó iṣẹ́ tí ó kéré jù lọ, owó ọ̀yà kéré, s. Salário mínimo. 
Iye owó tó wálẹ̀ jù lọ tí wọ́n ń ta, s. Preço mínimo. 
Ìdọ́gbọ́n fara mọ́, s. Conformidade mínima.
Gàgàgúgú, adj. Muito grande, pesado.
Gajù, gajùlọ̀, adj. Mais do que. Grau comparativo e superlativo de ser alto.
Gàgàrà, gagara, adj. Alto, comprido (não é usado para pessoas).

Kéré, v. Ser pequeno.
Kéré jú, v. Ser muito pequeno, menor.
Kéré júl, adj. Muito menor.
Kékèké, kékeré, kéékèèké, adj. Pequeno.
O, ò, pref. Adicionado ao verbo para formar substantivos que indicam alguém que faz.
O, òo, part. adv. 1. Forma frases exlamativas para ênfase. Ó ti dé o! - Ele já chegou! 2. A forma òo é usada para responder a uma saudação, caso não exista outra estabelecida, ou para concordância diante de uma outra expressão. Ẹ káalẹ́ o - Boa-noite; Òo (respondendo).

Òun, ó, pron. pess. Ele, ela.
O, pron. pess. Você 
, pron. Você. É usado dessa forma depois de verbo ou preposição.
, pref. Adicionado ao verbo para formar substantivos que indicam alguém que faz. Ọdẹ (caçador) e dẹ (caçar).
Ọ, ọ́, pron. da 3ª pessoa do singular representado pela repetição da vogal final do verbo de uma sílaba ( caso objetivo 3ª pessoa). Ó ṣọ́ - Ele vigiou, Ó ṣọ́ ọ - Ele a vigiou.
Ọ, ẹ, pron. oblíquo. Você.
Kò, ò, adv. Não. Faz a negativa dos verbos regulares.

Ti lọ, adj. Desaparecido.
, pron. rel. Que, o qual, do qual, cujo.
, conj. Se. Enquanto, ao mesmo tempo que.
, prep. Desde que.
, v. Bater com a mão ou com algo na mão, acertar o alvo.
, adv. Onde, quando.
Ti, prep. de ( indicando posse). Quando usado entre dois substantivos, usualmente é omitido. Ilé ti bàbá mi = ilé bàbá mi ( A casa do meu pai).
Ti, ti...ti, adj. Ambos... e. Ti èmi ti ìyàwó mi - ambos, eu e minha esposa.
Ti, v. Ter (verb. aux.). Arranhar. Pular.
Ti, v. interrog. Como. Ó ti jẹ́? - Como ele está.
Ti, adv. pré-v. Já. Indica uma ação realizada.
Ti, àti, conj. E.
Ti, part. pré-v. 1. Usada para indicar o tempo passado dos verbos. Èmi ti máa rìn lálé - Eu costumava caminhar à noite. 2. É usada com báwo ni - como - quando se deseja expressar sentimento e posicionada antes do verbo principal. Báwo ni àwọn ti rí? - Como eles estão?.
Tìti, adv. Tremendamente, violentamente.
Títí, adv. Continuamente, constantemente.
Títí, prep. Até.
Tìtì, adv. Tremulamente, balançadamente.
Títì, adj. Trancado, que deve ser empurrado, fechado.
Títì, ọ̀nà, s. Via pública, rua, passagem.
Ti... ti, adj. Ambos... e. Ti èmi ti ìyàwó mi - Ambos, eu e minha esposa.
Títi-àiyé, adv. Eternamente.
Títí dé, prep. Até. (referindo-se a um local ou espaço).
Títí di, prep. Até. (referindo-se a período de tempo).
Títí  láé, títí láí, adv. Perpetuamente, para sempre, definitivamente.

Iṣẹ́, s. Trabalho, serviço, ocupação. Mensagem.
Ọ̀kẹ́, s. Bolsa grande contendo 20 mil búzios; usado nos mitos de Ifá como medida padrão de oferenda.
Owó, s. Dinheiro, moeda.
Àpò, s. Bolso, bolsa, sacola, saco.
Owó ẹ̀rọ̀, s. Tipo de búzio pequeno.
Owó ẹyọ, s. Cauri (tipo de búzio um pouco maior).  
Àpò owó ẹyọ, s. Saco de cauris.
Oníṣirò, s. Contador.

Owó tí ń wọlé, s. Renda. Gbígbọ́ bùkátà: Ìpíndọ́gba iye tó ń wọlé lọ́dún fún ẹnì kọ̀ọ̀kan ní Gúúsù Aṣálẹ̀ Sàhárà ní Áfíríkà kò tó nǹkan - Subsistência: Renda per capita na África subsaariana não chega a 500 dólares por ano.

Owó tó ń wọlé lóṣù, owó tó ń wọlé fún ọ lóṣù lọ, owó tó ń wọlé ti oṣù, s. Rendimento mensal. Owó tó ń wọlé fún mi pọ̀, mo sì rí i pé mo lè ra ohunkóhun tó bá ti wù mí - Minha renda aumentou, e achava que podia comprar tudo o que quisesse. Irú èrò yìí lè mú kí ẹnì kan máa kópa nínú àwọn eré ìdárayá lẹ́yìn ilé ẹ̀kọ́ tàbí kó wẹgbẹ́ tí wọ́n máa ń dá sílẹ̀ nílé ẹ̀kọ́, ó lè mú kí ẹnì kan má máa san iye owó orí tó yẹ kó san lórí owó tó ń wọlé fún un, tàbí kó máa purọ́ bí wọ́n bá ní kó ṣàlàyé ohun kan tó lè dójú tini tó hù níwà -  Numa linha de raciocínio similar, alguém talvez participe em esportes ou outras atividades extracurriculares, não declare toda a renda tributável ou minta quando solicitado a revelar possíveis ações embaraçosas.
Gbogbo owó tó ń wọlé fún un kò tó nǹkan, s. Renda abaixo da linha de pobreza. Àìmọye oṣù ni owó kankan ò fi wọlé fún wa”- Ficamos sem fonte de renda por muitos meses.”
Owó tún ń wọlé sápò, s. Renda adicional. 
Fọ́ọ̀mù owó orí, s. Formulário de imposto. Àpẹẹrẹ àwọn tó ṣe tààràtà ni owó orí téèyàn ń san lórí iye tó ń wọlé fún un, owó orí táwọn iléeṣẹ́ máa ń san àti owó orí lórí nǹkan ìní - O imposto de renda de pessoas físicas, de pessoas jurídicas e os impostos sobre imóveis são exemplos de tributos diretos.
Owó tó ń wọlé fún ìdílé, s. Renda familiar. Owó tó ń wọlé fún ọ̀pọ̀ ìdílé lónìí ti fi ìlọ́po mẹ́ta ju iye tó ń wọlé fún àwọn ìdílé ní àádọ́ta ọdún sẹ́yìn - A renda da família mediana no mundo é três vezes maior hoje do que há 50 anos.
Owó orí ìjọba ìpínlẹ̀, s. Imposto de renda estadual.
Owó tó ń wọlé látinú tẹ́tẹ́ títa lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì, s. Renda do jogo por computador, renda de jogos de azar na internet. Lọ́dún 2001, wọ́n ti ju ẹgbẹ̀fà [1,200] lọ, ọdọọdún sì ni owó tó ń wọlé látinú tẹ́tẹ́ títa lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì ń fi ìlọ́po méjì ga sí i - Em 2001, mais de 1.200, e a renda do jogo por computador dobra a cada ano.




Nenhum comentário:

Postar um comentário