segunda-feira, 5 de outubro de 2020

- Papua Ocidental

Ilẹ̀ Apáìwọ̀orùn Papua, ilẹ̀ Ìwọòrùn Papua (Papua Ocidental). 



Ẹgbẹ́ Ọmọ Ogun Òmìnira Torílẹ̀-èdè fún ilẹ̀ Apáìwọ̀òrùn Papua.
Exército de Libertação Nacional da Papua Ocidental (TPNPB).



Àwọn ará papua ṣì ń jà fún òmìnira látọwọ́ àwọn ara Indonésíà.
Os papuas ainda lutam pela independência dos indonésios.

Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò, àkójọ ọ̀rọ̀ tí ò ń lò lójoojúmọ́, àwọn àkànlò ọ̀rọ̀, àwọn àkànlò èdè, ọ̀rọ̀ tó máa ń sọ, àkànlò èdè lọ́nà tó gún régé (vocabulário).


Nwọ́n, pron. pess. Eles, elas.  Expressa uma ação que não é creditada a nenhuma pessoa em particular.
Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas. É também usado como partícula para formar o plural do substantivo; neste caso, é posicionado antes do substantivo.
Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.
Wọn, pron. poss. Deles, delas
.

Ẹgbẹ́ Ọmọ Ogun Olùyọ̀ǹda Ara Ẹni fún Òmìnira Apáìwọ̀orùn ilẹ̀ Papua, s. Exército de Voluntários para a Independência da Papua Ocidental.

Ajàjàgbara, s. Revolucionário.

Ètò àwọn ọmọ ogun ọlọ̀tẹ̀ tó dìhámọ́ra, s. 

Organização dos insurgentes armados.

Fún, prep. Para, em nome de (indica uma intenção pretendida para alguém).
Nípa, nípasẹ̀, adv. Sobre, acerca de, concernente a. 
Orílẹ̀-èdè Olómìnira, s. República.
Orílẹ̀, s. Nome que denota um grupo de origem ou clã.
Orílẹ̀-èdè, s. Estado, nação.
Èdè, s. Idioma, língua, dialeto.
Olómìnira, adj. Independente.
Ilẹ̀, s. Terra, chão, solo.
Níhà, adj. e prep. No lado de, para.
Papua, s. Papua.
Ti, prep. de ( indicando posse). Quando usado entre dois substantivos, usualmente é omitido. Ilé ti bàbá mi = ilé bàbá mi ( A casa do meu pai).
Níhà ìwọòrùn, adj. Ocidental.
Ìwọòrùn, apáìwọ̀orùn, s. Ocidente.
, prep. Para, em direção a. Indica movimento direcional.
Ìsọdibiàmúsìn, 
ètò ijọba amúnisìn, s. Colonialismo.
Ìṣẹlẹ́yàmẹ̀yà, s. Racismo.
Ìninilára, s. Opressão.
Ifipabanilòpọ̀, s. Estupro.
Ikú, s. Morte.
Ìdáyàfò, s. Intimidação.
Ìlómìnira, s. Independência. 



Nenhum comentário:

Postar um comentário