Àwọn ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ Árábù.
Times de futebol árabes.
1. Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ torílẹ̀-èdè Sáúdí Arábíà (Al-Ahli Saudi Football Club).
2. Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ torílẹ̀-èdè Ìjíptì (Al-Ahli Sporting Club [Egito]).
Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò, àkójọ ọ̀rọ̀ tí ò ń lò lójoojúmọ́, àwọn àkànlò ọ̀rọ̀, àwọn àkànlò èdè, ọ̀rọ̀ tó máa ń sọ, àkànlò èdè lọ́nà tó gún régé (vocabulário).
Nwọ́n, pron. pess. Eles, elas. Expressa uma ação que não é creditada a nenhuma pessoa em particular.
Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas. É também usado como partícula para formar o plural do substantivo; neste caso, é posicionado antes do substantivo.
Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.
Wọn, pron. poss. Deles, delas.
Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀, s. Time de futebol.
Torílẹ̀-èdè, adj. Nacional, da nação.
Sáúdí Arábíà, s. Arábia Saudita.
Ilẹ̀ Kẹ́mẹ́ẹ̀tì, Kẹ́mẹ́ẹ̀tì, s. Kemet, Egito antigo. A palavra Kemet foi escrita em Medu Neter, linguagem escrita mais antiga da Terra, com quatro hieróglifos.
Ìjíptì, Ẹ́gíptì, Íjíbítì, s. Egito.
Orílẹ̀-èdè Olómìnira Árábù ilẹ̀ Ẹ́gíptì, s. República Árabe do Egito.
Árábù, lárúbáwá, s. Árabe.
Ìṣọ̀kan Àwọn Ẹgbẹ́ Agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ tó wà lára àwọn Lárúbáwá, Ìṣọ̀kan Àwọn Ẹgbẹ́ Agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ Árábù, Ìṣọ̀kan Àwọn Ẹgbẹ́ Àpàpọ̀ Agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ Árábù, s. União das Associações Árabes de Futebol.
Ìmùlẹ̀ Àwọn Orílẹ̀-Èdè Arébíà, s. Liga Árabe.
Orílẹ̀-èdè Olómìnira Aṣọ̀kan Árábù, s. República Árabe Unida.
Ẹgbẹ́ Àpapò Ọmọ yorùbá, s. Associação yorubá
Nenhum comentário:
Postar um comentário