Obìnrin dúdú kan tí ó jẹ́ ọlọ́rọ̀ tó sábà máa ń wọ àwọn aṣọ ìgbàlódé.
Uma preta rica que costuma usar roupas de grife (afropaty, preta patrícia).
Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i - Se você precisar de mais informações:
https://marciatravessoni.com.br/entretenimento/o-que-significa-ser-uma-afropaty-ou-preta-patricia/
Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò, àkójọ ọ̀rọ̀ tí ò ń lò lójoojúmọ́, àwọn àkànlò ọ̀rọ̀, àwọn àkànlò èdè, ọ̀rọ̀ tó máa ń sọ, àkànlò èdè lọ́nà tó gún régé (vocabulário).
Nwọ́n, pron. pess. Eles, elas. Expressa uma ação que não é creditada a nenhuma pessoa em particular.
Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas. É também usado como partícula para formar o plural do substantivo; neste caso, é posicionado antes do substantivo.
Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.
Wọn, pron. poss. Deles, delas.
Obìnrin ọlọ́rọ̀, s. Mulher rica.
Obìnrin dúdú kan tí ó jẹ́ ọlọ́rọ̀, s. Uma preta rica.
Obìnrin ọlọ́rọ̀ kan tó sábà máa ń wọ aṣọ ìgbàlódé, s. Patrioinha. Uma mulher rica que usa roupa de grife.
Obìnrin ọlọ́rọ̀ kan tó máa ń wọ aṣọ olówó-ńlá tàbí ohun-ọ̀ṣọ́ dídán yanranyanran, s. Patrioinha. Uma mulher rica que usa roupas caras ou joias brilhantes.
Obìnrin ọlọ́rọ̀ kan tó máa ń wọ aṣọ tó dáa gan-an, s. Patrioinha. Uma mulher rica que usa roupa magnífica.
Ọmọbìnrin bàbá olówó kan tó sábà máa ń wọ àwọn aṣọ ìgbàlódé, s. Patricinha. A filha de um pai rico que costuma usar roupas de grife.
Ọ̀dọ́bìnrin ọlọ́rọ̀ kan tí àwọn òbí rẹ̀ máa ń ra àwọn aṣọ ìgbàlódé fún un, s. Patricinha. Uma jovem rica cujos pais compram roupas de grife para ela.
Ọ̀dọ́bìnrin dúdú kan tí ó jẹ́ ọlọ́rọ̀ tí àwọn òbí rẹ̀ máa ń ra àwọn aṣọ ìgbàlódé fún un, s. Petricinha. Uma patricinha preta cujos pais compram roupas de grife para ela.
Nenhum comentário:
Postar um comentário