Agbègbè ọlọ́pọ̀ ilé Àfonífojì Oòrùn.
Condomínio Vale do Sol.
Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò, àkójọ ọ̀rọ̀ tí ò ń lò lójoojúmọ́, àwọn àkànlò ọ̀rọ̀, àwọn àkànlò èdè, ọ̀rọ̀ tó máa ń sọ, àkànlò èdè lọ́nà tó gún régé (vocabulário).
Nwọ́n, pron. pess. Eles, elas. Expressa uma ação que não é creditada a nenhuma pessoa em particular.
Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas. É também usado como partícula para formar o plural do substantivo; neste caso, é posicionado antes do substantivo.
Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.
Wọn, pron. poss. Deles, delas.
Àdúgbò tó ní géètì tí a ń pè ní Àfonífojì Oòrùn, s. Condomínio fechado chamado Vale do Sol.
Agbègbè ọlọ́pọ̀ ilé kan tí a ń pè ní Àfonífojì Oòrùn, s. Um Condomínio chamado Vale do Sol.
Agbègbè kan táwọn tó ti fẹ̀yìn tì lẹ́nu iṣẹ́ ń gbé, s. Um condomínio fechado de aposentados, uma área onde moram aposentados
Àwọn agbègbè ibùgbé tí ó ní ààbò híhá gádígádí, s. Áreas bem reservadas, áreas residenciais com alta segurança.
Agbègbè ọlọ́pọ̀ ilé, s. Condomínio, área residencial com várias unidades.
Àdúgbò tó ní géètì, s. Condomínio fechado.
Àfonífojì ọlọ́ràá kan tí àwọn òkè ẹlẹ́wà yí ká—àwọn kan kún fún òkúta, ewéko títutù yọ̀yọ̀ sì bo àwọn mìíràn, s. Vale de vegetação luxuriante, cercado por belas montanhas — algumas rochosas e outras cheias de vegetação.
Àfonífojì Hínómù, s. Vale de Hinom.
Àfonífojì olójú ọ̀gbàrá ti Kẹ́rítì, s. Vale da torrente de Querite.
Àfonífojì ọlọ́ràá, s.Vale fértil.
Ìsapá máa ń mérè wá, s. Vale a pena o esforço.
Níhà ìlà oòrùn Kòtò Àfonífojì Ńlá náà ní Áfíríkà, s. A leste do Grande Vale do Rift na África.
Kòtò Àfonífojì Ńlá, s. Vale da Grande Fenda.
Àfonífojì Kídírónì, s. Vale do Cédron.
Àfonífojì ibú òjìji, s. Vale da sombra tenebrosa, vale da sombra profunda.
Ọgọ́rùn-ún mẹ́rin (400) ṣékélì fàdákà, s. 400 siclos de prata. Ọgọ́rùn-ún mẹ́rin (400) ṣékélì fàdákà ni ilẹ̀ yìí jẹ́ - Esta terra vale 400 siclos de prata.
Àfonífojì Réfáímù, s. Vale de Refaim.
Àfonífojì Àwọn Ọmọ Hínómù, s. Vale dos filhos de Hinom.
Ẹnubodè àfonífojì, s. Portão do vale.
Àfonífojì Áánónì, s. Vale do Arnom.
Àfonífojì Iyọ̀, s. Vale do Sal.
Àfonífojì Éṣíkólì, s. Vale de Escol.
Àfonifojì Élà, s. Vale de Elá.
Ìṣòtítọ́ lérè, s. Vale a pena ser honesto.
Àfonífojì ìpinnu, s. Vale da decisão.
Níhà ìlà oòrùn Àfonífojì Tígírísì, s. A leste do vale do rio Tigre, lado oriental do Vale do Tigre.
Àfonífojì Àwọn Ọba, s. Vale dos Reis.
Àfonífojì Séréédì, s. Vale de Zerede.
Àfonífojì Ákórì, s. Vale de Acor.
Àfonífojì Ìran, s. Vale da Visão.
Àfonífojì Jọ́dánì, s. Vale do Jordão.
Àárín òkè méjì, s. Entre duas monhanhas.
Igi ọsàn wẹ́wẹ́ àti igi òroǹbó, s. Limeira-da-pérsia e a laranjeira.
Ẹranko armadillo, s. Tatu.
Àfonífojì, s. Vale.
Oòrùn, s. Sol.
Nenhum comentário:
Postar um comentário