Ìṣeọ̀rọ̀àwùjọ (sociologia)
1 - Ìṣẹlẹ́yàmẹ̀yà, s. Racismo.
2 - Aláìfẹ́irúẹ̀dáọmọẹnìkéjì, s. Racista.
3 - Àwùjọ, s. Sociedade.
4- Ètòìlú àwùjọ, s. Política social.
5. Sáyẹ́nsì àwùjọ, s. Ciência social.
6 - Onígbàngbà ìṣeọ̀rọ̀àwùjọ, s. Macrossociologia.
7 - Oníkékeré ìṣàgbéṣe, s. Micro agência.
8 - Oníkékeré ìṣeọ̀rọ̀àwùjọ, s. Microssociologia.
9 - Ìpele àwùjọ, s. Estrutura social.
10 - Ìtòlẹ́se àwùjọ, s. Estratificação social.
11 - Àtòsọ́tọ̀ àwùjọ, s. Classe social.
12 - Àṣà, s. Costume, hábito, moda.
13 - Ìyípòpadà àwùjọ, s. Mobilidade social.
14 - Ẹ̀sìn, s. Religião.
15 - Ìsọditaráayé, s. Secularização.
16 - Òfin , s. Lei.
17 - Ìyájú, s. Desvio.
18 - Ìpele àwùjọ àti ìṣàgbéṣe ẹnìkọ̀kan = Estrutura e agência.
19 - Àdìmúlẹ̀, s. Instituição.
20 - Àdìmúlẹ̀ ìlera, s. Instituição de saúde.
21 - Oníwòsàn, s. Médico.
22 - Ológun, s. Militar.
23 - Ìjẹníyà, s. Punição.
24 - Orí íńtánẹ́ẹ̀tì, s. On-line.
25 - Ìmọ̀ sáyẹ́nsì, s. Conhecimento científico.
26 - Àwọn aṣèwadìí àwùjọ, s. Investigações sociais.
27 - Aṣèwadìí ìdárasí, s. Pesquisa qualitativa.
28 - Aṣèwadìí ìpòsí, s. Pesquisa quantitativa.
29 - Àròjinlẹ̀, s. Teoria.
30 - Ilẹ̀ọbalúayé, ilẹ̀-Ọba, ilẹ̀jọba, s. Império.
31 - Àṣàpúpọ̀, s. Multiculturalismo.
32 - Ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ ẹ̀yà ènìyàn, s. Multiétnico, sociedade multiétnica.
33 - Ẹrú, s. Escravo.
34 - Oko ẹrú, òwò ẹrú, títà àti ríra ènìyàn, s. Escravidão, escravatura.
35 - Ogun Abẹ́lé, s. Guerra civil.
36 - Ogun, s. Guerra.
37 - Ogun Àgbáyé, s. Gerra mundial.
38 - Ogun Àgbáyé Kìíní, s. Primeira guerra mundial.
39 - Ogun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejì, Ogun Àgbáyé Kejì, s. Segunda guerra mundial.
40 - Ìjídìde, s. Revolução.
41 - Àbíníbí ará Amẹ́ríkà, s. Nativo americano.
42 - Ìjọba, s. Governo, reino.
43 - Irú ìjọba, s. Forma de governo.
44 - Ìjọbapọ̀, Orílẹ̀-èdè ìjọba àpapọ̀, Orílẹ̀-èdè àpapọ̀, s. Federal.
45 - Ilẹ̀ ọbalúayé, s. Imperial.
46 - Ọlọ́ba, àdájọba, ìdọ́bajẹ, s. Monarquia.
47 - Ìṣetọlọ́ba, s. Monarquismo.
48 - Ìjọba ológun, s. Junta militar.
49 - Ọlọ́ba pátápátá, s. Monarquia absoluta.
50 - Ọlọ́ba onílànàìrẹ́pọ̀, s. Monarquia constitucional.
51 - Ìjọba àìlólórí, s. Anarquismo.
52 - Òṣèlúaráìlú, s. Democracia.
53 - Òṣèlúaráìlú òṣèlú aṣojú, s. Democracia representativa.
54 - Orílẹ̀-èdè olómìnira, s. República.
55 - Ìṣẹ̀lẹ̀ ìdánilóró, s. Ataques ou atentado terrorista.
56 - Ìṣedánilóró, s. Terrorismo.
57 - Olùdánilóró, s. Terrorista.
58 - Ogun sí Ìṣedánilóró, s. Guerra ao terrorismo.
59 - Ìṣekọ́múnístì, s. Comunismo.
60 - Ìṣesósíálístì, s. Socialismo.
60 - Ìṣekápítálístì, ìṣeòwòèlé, s. Capitalismo.
61 - Ìjàkádì ipò, s. Luta de classe.
62 - Manifẹ́stò Kómúnístì, s. Manifesto comunista.
63 - Aṣeọ̀rọ̀-òkòwò olóṣèlú, s. Economista político.
64 - Aṣeròjinlẹ̀ olóṣèlú, s. Teórico político.
65 - Aṣeọ̀rọ̀-àwùjọ, onímọ̀ àwùjọ, s. Sociólogo.
66 - Àdéhún àwùjọ, májẹ̀mú àwùjọ, s. Contrato social.
67 - Ìdájọ́, s. Justiça.
68 - Àláfíà, s. Paz.
69 - Àwọn ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn, s. Direitos humanos.
70 - Bákannáà, adj. Igualitário, mesmo, idêntico, similar.
71 - Alájídìde, s. Revolucionário.
72 - Àwọn ọ̀nà ìmúwàyé, s. Meios de produção.
73 - Àwọn ẹ̀tọ́ ẹ̀dá, s. Direitos naturais.
74 - Òfin káríayé, s. Direitos internacional.
75 - Ìkéde Akáríayé fún àwọn Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn, s. Declaração Universal dos Direitos Humanos.
76 - Òṣèlú aláwùjọ, s. Social-democracia.
77 - Alágbáláayé, s. Universalista.
78 - Àgbáláayé, s. Universal.
79 - Àgbájọ, s. Organização.
80 - Àjọṣepọ̀, s. Federação.
81 - Ọ̀làjú, s. Iluminismo.
82 - Ìṣeolómìnira ijọ́hun, s. Republicanismo clássico.
83 - Ọ̀rọ̀-òfin, s. Jurisprudência.
84 - Ìmòye sáyẹ́nsì àwùjọ, s. Filosofia da ciência social.
85 - Ìṣiṣẹ́ìtòkòwò, ìtòkòwò, s. Economia.
86 - Ìtòkòwò olóṣèlú, s. Economia política.
87 - Ìmòye olóṣèlú, ìmọ̀-òye olóṣèlú, s. Filosofia política.
88 - Àwọn ọmọẹgbẹ́, s. Os membros.
89 - Àwọn ọ̀nà ìmúwàyé, s. Meios de produção.
Ìṣẹ̀lẹ̀ ifikuparaeni, s. Ataque suicida.