Sàyẹ̀nsì (ciência)
1- Mathimátíkì, ìmọ̀ ìṣírò, s. Matemática.
2 - Nọ́mbà àdábáyé, nọ́mbà àdábá, s. Números naturais.
3 - Nọ́mbà odidi, s. Números inteiros
4. Nọ́mbà oníìpín, s. Números racionais.
5 - Nọ́mbà gidi, s. Números reais.
6 - Nọ́mbà tóṣòro, s. Números complexos.
7 - Ẹyọ tíkòsí, s. Unidade imaginária.
8 - Nọ́mbà alòdì àti nọ́mbà adájú, s. Número negativo.
9 - Ìṣírò, s. Aritmética.
10 - Ìṣírò Statistiki, s. Estatística.
11 - Nọ́mbà áljẹ́brà, s. Número algébrico.
12 - Ìsọdipúpọ̀, s. Multiplicação.
13 - Ìròpọ̀, s. Adição.
14 - Ìpín, ìpífúnní, s. Divisão.
15 - Ìyọkúrò, s. Subtração.
16 - Àmìnọ́mbà , s. Numeral. É toda palavra que encerra a ideia de número.
17 - Jíómẹ́trì, s. Geometria.
18 - Alọ́poméjì, onílọ́poméjì, s. Quadrado.
19 - Anígunpúpọ̀, s. Polígono.
20 - Òbìrípo, s. Círculo.
21 - Nọ́mbà, òǹkà, iye, s. Número.
22 - Multiplicativos: expressam que um numero é múltiplo de outro:
Ìlọ́po méjì ( dobro, duplo, duplicação)
Ìlọ́po mẹ́ta (o triplo)
Ìlọ́po mẹ́rin (o quádruplo)
23 - Fracionados: indicam que um numero é fração do outro:
Ìdájì (metade)
Ìdáta, ìdámẹ́ta (a terça parte ou porção de algo ).
Ìdárún (quinta parte)
24 - Prefixos usados para formar os numerais adverbiais:
Lọ́kọ̀ọ̀kan = uma de cada vez.
Lẹ́ẹ̀kan = uma vez.
Lẹ́ẹ̀kíní = a primeira vez.
Ní méjèèjì = todos os dois, ambos.
Kíní-kíní = todo o primeiro.
Ìjẹta = três dias atrás.
Ìdájì = meio.
Ní méjìméjì = dois de cada vez.
Lẹ́ẹ̀méjì = duas vezes.
Lẹ́ẹ̀kéjì = a segunda vez.
Ní mẹ́tẹ̀ẹ̀ta = todos os três.
Kéjì-kéjì = todos os segundos.
Ìdúnta = três anos atrás.
Ìdámẹ́ta = um terço.
Ìdámẹ́rin = um quarto.
25 - Àwọn nọ́mbà ní yorùbá:
Números em yorubá:
0) Òdo, òfo.
Os números básicos.
1) Mení, oókan, ọ̀kan, kan, ení.
2) Méjì, èjì.
3) Mẹ́ta, ẹ̀ta.
4) Mẹ́rin, ẹ̀rin
5) Márùn-ún, márún, àrún.
6) Mẹ́fà, ẹ̀fà.
7) Méje, èje.
8) Mẹ́jọ, ẹ̀jọ.
9) Mẹ́sàn-án, mẹ́sàán, ẹ̀sán.
10) Mẹ́wàá, ẹ̀wá, ẹ̀wàá .
Entre onze e quatorze, os numerais ficam da seguinte forma.
11) Mọ́kànlá.
12) Méjìlá.
13) Mẹ́tàlá.
14) Mẹ́rìnlá.
Entre quinze e dezenove, conforme o número em questão, subtraímos qualquer um dos números que compõem os números básicos de número vinte.
15) Ẹ̀ẹ́dógún, Ẹ̀ẹ́dogún, márùn-dín-lógún, àrùndínlógún.
16) Mẹ́rin-dín-lógún.
17) Mẹ́ta-dín-lógún.
18) Méjì-dín-lógún.
19) Mọ́kàn-dín-lógún.
20) Ogún.
Entre vinte e vinte e quatro, adotamos o sistema de adição.
21) Mọ́kàn-lé-lógún.
22) Méjì-lé-lógún.
23) Mẹ́ta-lé-lógún.
24) Mẹ́rin-lé-lógún.
25) Márùn-dín-lọ́gbọ̀n.
26) Mẹ́rin-dín-lọ́gbọ̀n.
27) Mẹ́ta-dín-lọ́gbọ̀n.
28) Méjì-dín-lọ́gbọ̀n.
29) Mọ́kàn-dín-lọ́gbọ̀n.
30) Ọgbọ̀n.
31) Mọ́kàn-lé-lọ́gbọ̀n.
32) Méjì-lé-lọ́gbọ̀n.
33) Mẹ́ta-lé-lọ́gbọ̀n.
34) Mẹ́rin-lé-lọ́gbọ̀n.
35) Márùn-dín-lógójì.
36) Mẹ́rin-dín-lógójì.
37) Mẹ́ta-dín-lógójì.
38) Méjì-dín-lógójì.
39) Mọ́kàn-dín-lógójì.
50) Àádọ́ta, àádọ́ọ̀ta.
60) Ọgọ́ta, ọgọ́ọ̀ta.
70) Àádọ́rin, àádọ́ọ̀rin.
80) Ọgọ́rin, ọgọ́ọ̀rin.
90) Àádọ́rún, àádọ́ọ̀rún.
100) Ọgọ́rùn-ún, ọgọ́ọ̀rún
110) Àádọ́fà.
120) Ọgọ́fà.
130) Àádóòje.
140) Ogóòje.
150) Àádọ́òjọ.
160) Ọgọ́ọ̀jọ.
170) Àádọ́ọ̀sàn.
180) Ọgọ́ọ̀sàn.
190) Àádọ́wàá.
200) Igba.
300) Ọ̀ọ́dúnrún.
400) Irínwó.
500) Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta.
600) Ẹgbẹ̀ta.
700) Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rin.
800) Ẹgbẹ̀rin.
900) Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rún.
1000) Ẹgbẹ̀rún.
Nọ́mbà àkọ́kọ́, s, Número primo.
Nọ́mbà adọ́gba àti aṣẹ́kù, s. Números pares e ímpares.
Nọ́mbà onílọ̀ọ́pọméjì, s. Quadrado (aritmética).
Nọ́mbà alòdì àti nọ́mbà adájú, s. Número negativo.
Nọ́mbà tíkòsí, s. Número imaginário.