sábado, 18 de fevereiro de 2012

Banheiro

Ilétọ̀, ilé ìwẹ̀, balùwẹ̀ (banheiro)

Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).


Àpò tó kó ìgbẹ́, s. Bolsa de fezes, bolsa de colostomia.

Imí, ìgbẹ́, ìgbọ̀nsẹ̀, s. Estrume, excremento, esterco, fezes.
Oògùn apakòkòrò, s. Desinfetante.
Ilé ìgbọ̀nsẹ̀, ibi ìgbọ̀nsẹ̀s. Sanitário.
Ilé ìgbọ̀nsẹ̀, ilé ìyàgbẹ́, inú ilé ìgbọ̀nsẹ̀, ṣáláńgá, s.  Vaso sanitário.
Ṣáláńgá, s. Vaso sanitário, latrina (do hauçá sálgá).
Ṣáláńgá ló yẹ ká máa ṣe ìgbọ̀nsẹ̀ sí, s. Fossa séptica para o excremento humano.
Ibikíbi táwọn èèyàn bá ti ń ṣe ìgbọ̀nsẹ̀, s. Local de defecação.
Kọ́bọ́ọ̀dù ìkó-nǹkan-sí, s. Armário de pia.
Ẹnu ẹ̀rọ, ẹ̀rọ omis. Torneira. Tún ẹnu ẹ̀rọ tó bá ń jò ṣe - Conserte torneiras que estão vazando.
Ọpọ́n ìfọwọ́, s. Pia, lavatório.
Ọ̀ṣọ̀rọ̀, ọ̀ṣọ̀ọ̀rọ̀, s. Cascata, cachoeira, goteiras que caem do telhado, cano colocado no canto do telhado para colher a água da chuva, chuveiro.
Òjò, ọ̀wààrà-òjò, ọwọ́ òjò, s. Chuveiro (chuva súbita, abundante e passageira, pancadas de chuva).
Ilé ìwẹ̀, s. Casa de banho.
Ibi ìwẹ̀, s. Local de banho.
Dígí, àwòjíìji, s. Espelho.
Búrọ́ọ̀ṣì ìfọnu, búrọ́ọ̀ṣì ìfọyín, s. Escova de dente.
Bébà anùdọ̀tí, bébà ìnùdí, s. Papel higiênico.
Ọṣẹ, s. Sabonete.
Omi ọṣẹ, s. Sabão líquido.
Aṣọ ìnura, s. Toalha.
Kóòmù ìyarun, kóòmù, s. Pente.
Ọṣẹ ìfọyín, s. Pasta de dente, creme dental. 
Okùn ìfọyín, s. Fio dental. 
Ìnulẹ̀, s. Rodo.
Egbògi ìdíwọ́ bíbàjẹ́ nkanàpaàgùn ti ẹnu, s. Anti-séptico bucal.
Ààtàn, s. Lixo, pilha de estrume, montão de lixo.
Àkìtàn, àtìtàn, s. Refugo, lixo.
Ìdọ̀tí, s. Sujeira.
Lọ́fínńdà, s. Perfume.
Òórùn dídùn tó máa ń bo àágùn mọ́lẹ̀, s. Desodorante.
Ohun ìṣojúlóge, s. Maquiagem.
Ìfárùngbọ̀n tí ń lo iná mànàmáná, s. Barbeador elétrico.
Ìpara, s. Creme.
Ọpọ́n ìwẹ̀, s. Banheira.




Nenhum comentário:

Postar um comentário