quinta-feira, 9 de março de 2017

Cantiga de axé

CANTIGA DE AXÉ



BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈAṣẹ fún  

Àṣẹ Eṣù yóò bá ọ gbé làyè.

BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ 

Àṣẹ Ogún yóò bá ọ gbé làyè.

BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ 

Àṣẹ Ifá yóò bá ọ gbé làyè.

BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ 

Àṣẹ Ọbàtálá Ọbàtárià yóò bá ọ gbé làyè.

BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ 

Àṣẹ Odùdúwa yóò bá ọ gbé làyè.

BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ 

Àṣẹ Ọsányìn yóò bá ọ gbé làyè.

BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ 

Àṣẹ Ṣàngó yóò bá ọ gbé làyè.

BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ 

Àṣẹ Ọya yóò bá ọ gbé làyè.

BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ 

Àṣẹ Ọ̀ṣun yóò bá ọ gbé làyè.

BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ 

Àṣẹ Ọ̀bà yóò bá ọ gbé làyè.

BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ 

Àṣẹ Yemọja yóò bá ọ gbé làyè.


BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ 

Àṣẹ  Ọ̀ṣọọsì yóò bá ọ gbé làyè.

BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ 

Àṣẹ Ológún-ẹdẹ yóò bá ọ gbé làyè.

BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ 

Àṣẹ Òṣùmàrè yóò bá ọ gbé làyè.



BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ 

Àṣẹ Ọmọlú yóò bá ọ gbé làyè.


BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ 

Àṣẹ Ìbejì yóò bá ọ gbé làyè.

BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ 

Àṣẹ Ọbalúwayé yóò bá ọ gbé làyè.

BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ 

Àṣẹ Òrìṣà oko yóò bá ọ gbé làyè.

BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ 

Àṣẹ Egúngún yóò bá ọ gbé làyè.

BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ 

Àṣẹ Gẹ̀lẹ̀dẹ́ yóò bá ọ gbé làyè.


BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!
ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ 

Àṣẹ Ìrókò yóò bá ọ gbé làyè.

BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!

ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ 


Àṣẹ Orí rẹ yóò bá ọ gbé làyè.

BÀBÁLÓRÌṢÀ: Aṣẹ, aṣẹ o!

ÉGBÈ: Aṣẹ fún ọ

Àṣẹ ọ̀kanlénígba imalẹ̀ yóò bá ọ gbé làyè. 


Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).

1. Aṣẹ, aṣẹ o.
 Assim será, assim será.

Aṣẹ, s. Força, poder, o elemento que estrutura uma sociedade, lei, ordem. Palavra usada para definir o respeito ao poder de Deus, pela crença de que é Ele que tudo permite e dá a devida aprovação.
O, part. adv. Forma frase exclamativa para ênfase. Ó ti dé o! - Ela já chegou! 

2. Aṣẹ fún ọ.
Assim será para você.

Égbè, s. Coro, coral. Ajuda, apoio, parcialidade.
Fún, prep. Para, em nome de (indica uma intenção pretendida para alguém).
, pron. Você. É usado dessa forma depois de verbo ou preposição

3. Àṣẹ ọ̀kanlénígba imalẹ̀ yóò bá ọ gbé làyè.
Axé das duzentas e uma divindades vai acompanhar você por toda vida.

Ọ̀kanlénígba, num. Duzentos e um (201).
Imalẹ̀, s. Embema do culto aos ancestrais, divindade, orixá.
Yóò, adv. pré. v. Indicador de futuro numa frase afirmativa. Em outras palavras, emprega-se o futuro do presente para expressar uma ação que será executada no futuro. Outros indicadores de futuro: yóó, ó, á, máa, fẹ́.
, v. Acompanhar, ajudar. Alcançar, ultrapassar, perseguir. Encontrar., atingir.
Gbé, v. Carregar, levantar, erguer, morar, viver).
Láyè, láàyè, adj. Vivo.
Àyè, s. O fato de estar vivo.
Ìyè, ẹ̀mí, wíwà láàyè: ìgbésí ayé, ayé, s. Vida.
Wíwà. s. Estado de ser , de existir.

4. Àṣẹ Orí rẹ yóò bá ọ gbé làyè.
 O axé do seu Orí vai acompanhar você por toda a vida.

Orí, s. Cabeça.
Rẹ, ẹ, pron. poss. Seu, sua, de você. É posicionado depois de substantivo.

Àkójọ àwọn ìwé ti wádìí lẹ́nu (lista de livros pesquisados, bibliografia)


SÀLÁMÌ, Sikiru. 
           Cânticos dos Orixás na África/ Sikiru Sàlámì King. São Paulo: Oduduwa, 1992.

BENISTE, José.

          Dicionário yorubá-português/ José Beniste. - Rio de Janeiro: Bertrand Brasil, 2011.

Nenhum comentário:

Postar um comentário