Àṣà ọmọ Áfíríkà Bòlífíà.
Cultura afroboliviana.
Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀ (Vocabulário).
Ìṣẹ̀ṣe, àṣà àtọwọ́dọ́wọ́, òfin àtọwọ́dọ́wọ́, s. Tradição.
Ìṣẹ̀dálẹ̀, s. Costume primitivo, início.
Àṣà, s. Costume, hábito, moda.
Àtọwọ́dọ́wọ́, adj. Hereditário, tradicional.
Ọmọ Áfíríkà Bòlífíà, s. Afroboliviano.
Ọmọkùnrin Áfíríkà Bòlífíà, s. Homem afroboliviano.
Ọmọbìnrin Áfíríkà Bòlífíà, s. Mulher afroboliviana.
Ọmọ Áfíríkà Amẹ́ríkà, aláwọ̀dúdú Ará Amẹ́ríkà, adúláwọ̀ ará Amẹ́ríkà, s. Afro-americano, afro-estadunidense, africano-americano.
Ọmọ Áfríkà Bràsíl, aláwọ̀dúdú ará Bràsíl, adúláwọ̀ ará Bràsíl, s. Afro-brasileiro.
Ọmọ Áfríkà Ásíà, s. Afro-asiático.
Ọmọ Áfríkà Kàríbẹ́ánì, aláwọ̀dúdú ará Kàríbẹ́ánì, adúláwọ̀ ará Kàríbẹ́ánì, s. Afro-caribenho.
Ọmọ Áfríkà Kúbà, aláwọ̀dúdú ará Kúbà, adúláwọ̀ ará Kúbà, s. Afro-cubano.
Ní ti Áfríkà, ti orílẹ̀ èdè Áfríkà, adj. Africano.
Ọmọ ilẹ̀ Áfríkà, s. Africano.
Ọmọ kùnrin ilẹ̀ Áfríkà, s. Homem africano, africano.
Ọmọbìnrin ilẹ̀ Áfríkà, s. Mulher africana, africana.
Ọmọ, s. Filho, criança, descendência.
Ìpínlẹ̀ Ogunlọ́gọ̀ Orílẹ̀-èdè ilẹ̀ Bòlífíà, s. Estado Plurinacional da Bolívia.
Ogunlọ́gọ̀ Orílẹ̀-èdè, s. Plurinacional.
Ilẹ̀ Bòlífíà, Bòlífíà, s. Bolívia.
Áfríkà, Áfíríkà, s. África.
Nenhum comentário:
Postar um comentário