sábado, 27 de maio de 2017

Dança Tradicional Congolesa.


Ijó àtọwọ́dọ́wọ́ ti orílẹ̀ èdè Kóngò.
Dança Tradicional Congolesa.  




Àkójọ́pọ̀ Itumọ̀ (Glossário).
Ìwé gbédègbéyọ̀  (Vocabulário).

Ijó, s. Dança.
Ìṣẹ̀ṣe, àṣà àtọwọ́dọ́wọ́, òfin àtọwọ́dọ́wọ́, s. Tradição. 
Ìṣẹ̀dálẹ̀, s. Costume primitivo, início. 
Àṣà, s. Costume, hábito, moda.
Àtọwọ́dọ́wọ́, adj. Hereditário, tradicional.
Ọmọorílẹ̀-èdè Kóngò, ọmọ ilẹ̀ Kóngò, ọmọkùnrin ilẹ̀ Kóngò, s. Congolês.
Ọmọkùnrin ilẹ̀ Kóngò, s. Congolês do sexo masculino.
Ọmọbìnrin ilẹ̀ Kóngò, s. Congolesa.
Ní ti Kóngò, ti orílẹ̀ èdè Kóngò, adj. Congolês.
Orílẹ̀-èdè Olómìnira Olóṣèlú ilẹ̀ Kóngò, s. República Democrática do Congo.
Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Kóngò, s. República do Congo, Congo-Brazzaville ou Congo-Brazavile.

Nenhum comentário:

Postar um comentário