quarta-feira, 19 de dezembro de 2018

Cores

 ÀWỌN ÀWỌ̀ (CORES):

1. CORES: àwọ ayinrin,  àwọ ojú ọ̀run, 
àwọ  búlúù (cor azul), àwọ (cor lilás), àwọ dúdú (cor preta), àwọ ọsàn,  àwọ omi ọsàn (cor laranja), àwọ ara, àwọ pákó, àwọ ilẹ̀ (cor marrom), àwọ búráùn, àwọ búráwùn (marrom, castanho),  àwọ elésè àlùkò,  àwọ àlùkò  (cor púrpura, roxo), àwọ èèrú, àwọ éérú, àwọ eléérú (cor cinza), àwọ pupa (cor vermelha), àwọ pupayòyò (cor escarlate), àwọ ewé,  àwọ ewéko (cor verde), àwọ osùn (cor violeta), àwọ ẹlú (cor índigo), àwọ funfun (cor branca), àwọ òféfe,  àwọ sánmà (cor azul claro), àwọ èsè, àwọ pupa rúsúrúsú, àwọ yẹ́lò (cor amarela).

2. CORES DO ESPECTRO DE LUZ: pupa (vermelho), ọsàn (laranja), èsè (amarelo), ewé (verde), àyìnrín (azul), èlú (índigo, anil), aró (violeta).


Resultado de imagem para cores do espectro

Nenhum comentário:

Postar um comentário