terça-feira, 25 de fevereiro de 2025

Exu Tranca-Rua

 

Èṣù Olùdènà ìgboro (Exu Tranca-Rua)


Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò, àkójọ ọ̀rọ̀ tí ò ń lò lójoojúmọ́, àwọn àkànlò ọ̀rọ̀, àwọn àkànlò èdè, ọ̀rọ̀ tó máa ń sọ, àkànlò èdè lọ́nà tó gún régé (vocabulário).

Nwọ́n, pron. pess. Eles, elas. Expressa uma ação que não é creditada a nenhuma pessoa em particular.

Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas. É também usado como partícula para formar o plural do substantivo; neste caso, é posicionado antes do substantivo.

Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.

Wọn, pron. poss. Deles, delas.

Èṣù tó máa ń dí ọ̀nà, s. O Exu que bloqueia o caminho

Èṣù tó máa ń dí ojú pópó, Èṣù tó máa ń dí òpópónà, s. Exu que bloqueia a estrada.

Èṣù tó máa ń dí ọ̀nà ìgboro, s. Exu que bloqueia a via pública

Èṣù tí máa ń dá wa dúró lójú ọ̀nà, s. O Exu que nos detém no caminho.

Èṣù tí máa ń dúró sójú ọ̀nà, s. Exu que está no caminho.

Olùdènà, adènà, s. Guardião de portão, guardião que bloqueia o caminho.

Ìsénà, s. Bloqueio, obstáculo. 

Ìrin ìdábùú, ọ̀pá ìdábùú, s. Tranca, aquilo que impede ou atrapalha, atravanco, barreira, bloqueio.

Àwọn ìkọ́, s. Ganchos.

Tó máa ń sọ ọ̀pá ìdábùú àwọn ẹnubodè rẹ di alágbára, adj. Que reforça as trancas dos seus portões.
Àwọn asọ̀ tí ó dà bí ọ̀pá ìdábùú ilé gogoro ibùgbé, s. Contendas que são como a tranca duma torre de habitação.
Dènà, v. Armar uma cilada, emboscar, atocaiar.
, v. Represar, bloquear. Fechar, trancar. Errar o alvo, errar o caminho
Sénà, v. Fechar, bloquear uma estrada.
Sèdíwọ, v. Bloquear.
Padé, v. Fechar. Usado para porta ou caixa que tenha uma parte fixa ou que tenha fecho.
, v. Fechar, trancar. Empurrar. Apoiar, firmar. Ser adjacente, ser próximo.
, v. Obstruir, bloquear, fechar, tapar buracos.
Tó ti dí ọ̀nà, adj. Que bloqueou o caminho.
Tó ti pa ojú yín dé, adj. Que fechou seus olhos.
Títì, adj. Trancado, que deve ser empurrado, fechado.
Ibi ìkẹyìn táwọn ẹ̀ṣọ́ ojú ọ̀nà wà láàárín ibi táwọn ọmọ ogun àwọn ọlọ̀tẹ̀ ń ṣàkóso àti ibi tí ìjọba ń ṣàkóso, s. Último bloqueio entre os territórios ocupados pelos rebeldes e os controlados pelo governo
Òpópónà tí ó ti dí, s. Rua bloqueada, estrada bloqueada.
Ilẹ̀kùn náà tó ti wà ní títì pa, s. A porta que já está trancada.
Ìta, ọ̀nà ìgboro ìlú, òpópó, òpópónà, ojúde, s. Rua.

Nenhum comentário:

Postar um comentário