terça-feira, 25 de fevereiro de 2025

Ọ̀rọ̀ tó gùn jùlọ nínú èdè Potogí tí a kọ sínú ìwé atúmọ̀ èdè (a palavra mais longa da língua portuguesa registrada em um dicionário)


Àrùn ẹ̀dọ̀fóró kan tí fífa eérú látinú òkè ayọnáyèéfín símú ń fà.

Pneumoultramicroscopicossilicovulcanoconiótico (uma doença pulmonar causada pela inalação de cinzas vulcânicas).


Ọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ tó wà nínú èdè, àwọn ọ̀rọ̀ tó máa lò, àkójọ ọ̀rọ̀ tí ò ń lò lójoojúmọ́, àwọn àkànlò ọ̀rọ̀, àwọn àkànlò èdè, ọ̀rọ̀ tó máa ń sọ, àkànlò èdè lọ́nà tó gún régé (vocabulário).


Nwọ́n, pron. pess. Eles, elas. Expressa uma ação que não é creditada a nenhuma pessoa em particular.

Àwọn, wọ́n, pron. Eles, elas. É também usado como partícula para formar o plural do substantivo; neste caso, é posicionado antes do substantivo.

Wọn, pron. oblíquo. A eles, a elas.

Wọn, pron. poss. Deles, delas.

Àrùn ẹ̀dọ̀fóró, s. Doença pulmonar.

Àwọn àrùn ẹ̀dọ̀fóró tí mímú tábà ń fà, s. Doenças pulmonares que costumam ser vinculadas ao tabagismo.

Eérú tí ń tú jáde nínú òkè ayọnáyèéfín, s. Cinzas saindo de um vulcão.

Eérú látinú òkè ayọnáyèéfín, s. Cinzas de um vulcão.

Eérú gbígbóná, s. Cinzas quentes.

Òkè ayọnáyèéfín, s. Vulcão.

 Ilẹ̀ erùpẹ̀ ọlọ́ràá láti inú òkè ayọnáyèéfín, s. Solo fértil de um vulcão.

Àìsàn tó jẹ mọ́ mímí ń ṣe, èyí tí afẹ́fẹ́ olóró àti àwọn èròjà àpáta kíkúnná tó tinú òkè ayọnáyèéfín jáde fà, s. Doença respiratória causada pelo ar tóxico e cinzas vulcânicas.

Fa èéfín sìgá wọn símú, v. Inalar a fumaça do cigarro.

Fífa èéfín sínú ẹ̀dọ̀fóró, s. Inalação de fumaça.

Ṣàlàyé ìdí tí fífa ẹ̀jẹ̀ tí a fi tọrẹ síni lára kò fi bójú mu, v. Explicar por que as transfusões de sangue doado não são apropriadas.


Nenhum comentário:

Postar um comentário